Eyi ni bi awọn Fulani afẹmiṣofo ṣe pa aadọta eeyan laarin ọjọ mẹrin

Adewumi Adegoke Titi di ba a ṣe n sọ yii inu ibẹru-bojo ni awọn eeyan abule…

Inu baagi ti baba olowo yii n gbe lọ si Inidia lo ko oogun oloro rẹpẹtẹ si

Jọkẹ Amọri Orileede India ni ọkunrin kan ti gbogbo eeyan mọ si baba olowo laduugbo wọn,…

Inu bi ṣọja, o yinbọn pa ṣọja ẹgbẹ ẹ mẹta, loun naa ba yinbọn jẹ

 Faith Adebọla  Ileeṣẹ ologun ilẹ wa lawọn ti bẹrẹ iwadii, lati mọ ohun to ṣokunfa iṣẹlẹ…

Iṣẹlẹ to ṣẹlẹ laipẹ yii ko ba ajọṣe emi atiyawo mi jẹ o-Wasiu Ayinde

Ọrẹoluwa Adedeji Mayegun ilẹ Yoruba, to tun jẹ ọkan pataki ninu awọn onifuji ilẹ wa, Alaaji…

Ara meriyiri! Babalawọ wọṣọ oogun lọ si banki

Faith Adebọla  Bo ba jẹ ori tẹlifiṣan tabi lori fọnran ni aworan naa ti jade ni,…

O ma ṣe o, Fadeyi Oloro onitiata ti ku o!

Faith Adebọla Gbajugbaja irawọ oṣere tiata ilẹ wa nni, Ojo Arowoṣafẹ, ti gbogbo eeyan mọ si…

Oyetọla dupẹ pe Tinubu wọle aarẹ, o loun naa maa pada sipo gomina laipẹ

Faith Adebọla Yooba bọ, wọn lọrọ to ba da ni loju ki i kọsẹ lete, gomina…

Ero rẹpẹtẹ pada lẹyin Fọlarin, wọn ni Makinde lawọn n ba lọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Nnkan ko ṣenuure fun oludije fun ipo gomina ipinlẹ Ọyọ lorukọ ẹgbẹ oṣelu…

Tinubu yan agbẹjọro aadọta lati koju awọn alatako to gbe e lọ sile-ẹjọ

Orẹoluwa Adedeji Awọn agbẹjọro bii aadọta ni aarẹ ti wọn ṣẹṣẹ dibo yan nilẹ wa lati…

Nitori ohun to ṣẹlẹ si i, oṣere ilẹ wa yii bu sẹkun gbaragada

 Jọkẹ Amọri Gbogbo awọn ti wọn ri oṣere ilẹ wa to ṣẹṣẹ bi ibeji laipẹ yii…

Esi idibo aarẹ yii ko tẹ awọn ọmọ Naijiria lọrun o, ki INEC ṣatunṣe lori ẹ – Amẹrika

Monisọla Saka  Aṣoju orilẹ-ede Amẹrika lorilẹ-ede Naijiria, Mary Beth Leonard, ti sọ pe ibo aarẹ ọdun…