Lori ọrọ ti ko to nnkan, Ọpẹyẹmi ti iya agbalagba lulẹ, niyẹn ba gbabẹ ku l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Nibi ti wọn ba ti n gbadura pe k’Ọlọrun ma jẹ ka ba…

Esi idibo aarẹ: Atiku ṣaaju awọn to ṣewọde lọ sọfiisi INEC

Faith Adebọla Eruku nla lo n sọ lọwọ bayii niwaju ọfiisi apapọ ajọ eleto idibo ilẹ…

Ko saaye lati tun hu oku akẹkọọ Chrisland fun ayẹwo mi-in – Ijọba Eko

Faith Adebọla Ijọba ipinlẹ Eko ti lawọn o ni in lọkan, awọn o si ni i…

Lẹyin to yege ibo aarẹ, Tinubu ṣabẹwo si Ọba Akiolu l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko Bii igba tawọn jagunjagun aye ọjọun ba jagun ajaye, ti wọn si fẹẹ…

Ẹ woju awọn adigunjale to n yọ wọn lẹnu l’Ajegunlẹ Faith Adebọla, Eko

Faith Adebọla Mẹfa ni wọn, gende si ni wọn, ọjọ-ori wọn ko ju aarin ọdun mejidinlogun…

Dubai ni Sharafa n gbe egboogi oloro lọ tọwọ fi tẹ ẹ

Faith Adebọla A ki i sọ fọmọde pe ko ma ṣe dẹtẹ, to ba ti le…

‘Emi ni mo ṣa akẹkọọ fasiti yii pa nitori mo ti fowo to ni ki n fi b’oun wale ta tẹtẹ’

Ọrẹoluwa Adedeji Epe rabandẹ rabandẹ lawọn eeyan n gbe ọkunrin abaniwale kan, Shagbaor Ugosor Japhet ṣẹ…

                                                                                                                                                                                                                                                                                      ‘Emi ni mo ṣa akẹkọọ fasiti yii pa nitori mo ti fi owo to ni ki n ba oun fi wale ta tẹtẹ’                                                                                             ‘Emi ni mo ṣa akẹkọọ fasiti yii pa nitori mo ti fi owo to ni ki n ba oun fi wale ta tẹtẹ’

Faith Adebọla A ki i sọ fọmọde pe ko ma ṣe dẹtẹ, to ba ti le…

Idowu ji ọga rẹ gbe, lo ba yin in lọrun pa

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn ẹbi oniṣowo kan, Ọmọlolu Olowoṣọyọ ti kọwe ifẹhonu han si ọfiisi ọga…

Ezeife koro oju si ajọ INEC, o ni oriire ijawe olubori Tinubu ko le tọjọ

Monisọla Saka Baba agbalagba ilẹ Ibo to ti figba kan ṣe gomina ipinlẹ Anambra ri, Chukwuemeka…

O ma ṣe o, ọmọ Ṣani Abacha ku lojiji, wọn lo toju oorun doju iku ni

Jọkẹ Amọri Titi ba a ṣe n sọ yii ni awọn eeyan ṣi n ba mọlẹbi…