Ẹ maa na gbogbo owo atijọ ati tuntun lọ titi dipari ọdun yii-Ile-ẹjọ to ga ju lọ

Faith Adebọla Ile-ẹjọ giga ju lọ nilẹ wa ti paṣẹ pe nina lowo, ko si aṣadanu…

O san ki Atiku pada si Dubai rẹ, ti ko ba gba pe emi ni mo wọle ibo aarẹ- Tinubu

Monisọla Saka Aṣiwaju Bọla Ahmed Tinubu, ti i ṣe aarẹ ti wọn ṣẹṣẹ dibo yan ti…

Arẹgbẹṣọla ranṣẹ ikini ku oriire si Aṣiwaju Tinubu

Monisọla Saka Minisita fọrọ abẹle nilẹ wa, Ọgbẹni Rauf Arẹgbẹṣọla, ti ki aarẹ tuntun ti wọn…

Emi ni wọle ibo aarẹ, mo si maa fi ẹri han pe loootọ loootọ, ẹgbẹ wa lo jawe olubori-Obi

Jọkẹ Amọri Oludije sipo aarẹ fun ẹgbẹ oṣelu Labour, to tun jẹ gomina ipinlẹ Anambra nigba…

Ọlọpaa yii yinbọn para ẹ lẹyin to pa ọrẹbinrin ẹ tan ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’Ọjọbọ, Tọsidee, ọjọ kẹji, oṣu Keta, ni Sajẹnti ọlọpaa kan, Ọlalere Michael, ṣeku…

Ori gbigbẹ ati tutu mẹsan-an pẹlu ẹya ara eeyan mi-in ni wọn ka mọ awọn eleyii lọwọ n’Ibadan

Ọlawale Ajao Niṣe ni ọpọ awọn to wa nibi ti ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọyọ ti ṣafihan…

Ayẹwo ti fihan pe ọmọ mi gan mọna nileewe Chrisland ni o-Adeniran

Faith Adebọla, Eko Iya Whitney Adeniran, ọmọọdun mejila to n kawe nileewe Chrisland Group of Schools,…

Nitori esi idibo, awọn obinrin bẹ alalẹ lọwẹ ni Kogi  

 Adegoke Adewumi Awọn obinrin kan lati Aarin Gbungbun ipinlẹ Kogi, ti fẹhonu wọn han nitori abajade…

Eto ikaniyan yoo mu igba ọtun wọ ilẹ Naijiria – Hundeyin 

Monisọla Saka Kọmiṣanna ijọba apapọ fun ileeṣẹ eto ikaniyan nipinlẹ Eko, National Population Commission, (NPC), Amofin…

EFCC ti mu Shuaib, ọpọlọpọ igbo ni wọn ba lọwọ ẹ n’Ilọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ajọ to n gbogun ti iwa ibajẹ nilẹ yii, EFCC ti mu arakunrin…

Nitori ẹsun jibiti, adajọ sọ Ayuba sẹwọn ọdun mẹfa ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’Ọjọruu, Wẹsidee, ọjọ kin-ni-in, oṣu Kẹwaa yii, ni ile-ẹjọ giga kan to filu…