Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ko ti i ṣeni to mọ awọn to ṣeku pa baba ẹni aadọta…
Author: admin
Eeyan meji ku lasiko rogbodiyan to ṣẹlẹ n’Ikarẹ-Akoko
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Eeyan meji lo ku, nigba tawọn mi-in tun fara gbọta, lasiko rogbodiyan tuntun…
Eyi laṣiiri to wa nidii miliọnu rẹpẹtẹ ti wọn ṣeeṣi san si akaunti Rafiu oni POS
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Asiri bi ajọ to n gbogun ti iwa jibiti ati ṣiṣe owo ilu…
Ko si olori gidi kan to maa lọ fun isinmi lakooko to ba n sin ilu lọwọ -Peter Obi
Adewale Adeoye Ondije dupo aarẹ orileede yii ninu ibo gbogbogboo to waye lọjọ kẹẹdọgbọn, oṣu keji ọdun…
Lẹyin tawọn ọmọ ẹgbẹ okunkun yinbọn pa Samad tan, wọn yọ oju, wọn tun ge ọwọ ẹ lọ n’Ilọrin
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọdọmọkunrin ẹni ọdun mẹtalelogun kan, Samad, to n wa Maruwa, ti dero ọrun…
Tọpẹ ati Nojeem ji epo ẹronpileeni ta, ni wọn ba dero Alagbọn
Faith Adebọla, Eko Awọn ọrẹ meji kan, Tọpẹ Ojo ati Najeem Haruna, tọwọ awọn agbofinro tẹ…
Fufu ni Barakat fẹẹ lọọ ra ti wọn fi fipa ba a laṣepọ, ti wọn si pa a n’Ibadan
Ọlawale Ajao, Ibadan Inu ọfọ ni idile ọmọbinrin ẹni ọdun mẹẹẹdọgbọn (25) kan to n jẹ…
Nitori ẹsun ole, baba yii febi pa awọn ọmọ ẹ titi ti meji fi ku ninu wọn
Faith Adebọla, Ogun Okun to gbe aparo baale ile ẹni ọdun marundinlaaadọta kan, Gbenga Ogunfadekẹ yii, ki…
Inu ọgba ẹwọn ti Raheed wa lo ti tun n ta igbo, ladajọ ba fi kun ẹwọn rẹ
Adewale Adeoye Bi wọn ba n wa ọdaran-mọran ẹyẹ to n mu ọsan lori iso, apẹẹrẹ…
Iru ki waa leleyii! Erinmilokun pa alaboyun kan
Monisọla Saka Lọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọjọ kejidinlogun, oṣu Kẹrin, ọdun yii, ni obinrin alaboyun kan nipinlẹ…
Isiaq at’ọrẹ ẹ yoo pẹ lẹwọn o, kòkò ìdáná, kula ounjẹ ati ọkada ni wọn ji gbe
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ile-ẹjọ Majisireeti kan to fikalẹ siluu Ilọrin, nipinlẹ Kwara, ti paṣẹ pe ki…