Dapọ Abiọdun yi orukọ ileewe TASCE pada si Sikiru Adetọna College of Education

Gbenga Amos, Ogun  Ni wara-n-ṣe-ṣa, bẹrẹ lati ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọjọ kejilelogun, oṣu Kọkanla, ọdun 2022…

TOM gba Adeleke nimọran: Tẹsiwaju ninu awọn eto rere tijọba Oyetọla ba ṣe

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ẹgbẹ kan ti ki i ṣe tijọba, The Osun Masterminds, ti gba gomina…

Atiku ṣa fẹẹ fọwọ ara ẹ ṣera ẹ ṣaa

Ayọdele Fayọṣe, ọkan pataki ninu awọn aṣaaju ẹgbẹ oṣelu PDP sin Atiku Abubakar ni gbẹrẹ ipakọ,…

Nitori ẹsun idigunjale ati ifipabanilopọ, adajọ ni ki wọn lọọ yẹgi fun Deji atọrẹ ẹ l’Ekiti

Adewumi Adegoke Ile-ẹjọ giga kan niluu Ado Ekiti, nipinlẹ Ekiti, ti paṣẹ pe ki wọn lọọ…

Buhari yoo ṣiṣọ loju owo Naira wa ti wọn fẹẹ pa awọn rẹ da

Jọkẹ Amọri Ọjọruu, Wẹsidee, ọjọ kẹtalelogun, oṣu Kọkanla, ọdun yii, ni Aarẹ Muhammadu Buhari yoo ṣiṣọ…

Nitori ọrọ ti ko to nnkan, Esther gun ọrẹkunrin ẹ lọbẹ pa

Faith Adebọla, Eko Abamọ, a o ṣe e, a ṣe e tan, o daapọn, bẹẹ lọrọ…

Ile-ẹjọ paṣẹ fun ajọ eleto idibo lati bẹrẹ iforukọsilẹ pada

Adewumi Adegoke Lọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọjọ kejilelogun, oṣu Kọkanla yii, ni Adajọ Inyang Ekwo, ti ile-ẹjọ…

Atiku ati igbakeji rẹ ṣabẹwo si ẹgbẹ awọn Onigbagbọ

Lọla Ojo Awọn oludije funpo aarẹ ati igbakeji ninu ẹgbẹ oṣelu PDP naa ti ṣabẹwo si…

Ijọba Ọṣun yan alaga ẹgbẹ APC gẹgẹ bii Ọwa Igbajọ tuntun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Lẹyin ọpọlọpọ awuyewuye, ijọba ipinlẹ Ọṣun ti fọwọ si yiyan alaga ẹgbẹ oṣelu…

Ẹ ma dibo fẹgbẹ to ba fa aarẹ ati igbakeji to jẹ ẹlẹsin kan naa silẹ – Biṣọọbu Katoliiki

Faith Adebọla Yoruba bọ, wọn logun awitẹlẹ ki i pa arọ, arọ to ba gbọn si…

Aafaa Sule gbe iyaale ile lọ sotẹẹli, niyẹn ba ku sibẹ

Monisọla Saka Lọjọ Abamẹta, Satide, ọjọ kọkandinlogun, oṣu Kọkanla, ọdun yii, ni alamoojuto otẹẹli kan lagbegbe…