Adewale Adeoye Fun awọn kọọkan ti wọn ko mọ tẹlẹ pe ki i ṣohun to da…
Author: admin
Wọn ti mu Ojo o, awọn oni POS lo n lu ni jibiti l’Akurẹ
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn afurasi oníjìbìtì mẹta ni wọn ti wa lakolo ajọ sifu difensi, nipinlẹ…
Ẹṣọ alaabo pa agbebọn kan, wọn tun gba awọn ti wọn ji gbe silẹ l’Akoko
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Nnkan o ṣẹnuure fun ikọ awọn agbebọn kan ti wọn ji arinrin-ajo mẹtala…
A maa ṣofin lati daabo bo ẹtọ ati dukia awọn ọmọ oniluu l’Ekoo- Ọbasa
Faith Adebọla Ofin tuntun kan, eyi ti ileegbimọ aṣofin Eko lawọn maa po pọ, tawọn yoo…
Aṣiri tu: Ẹrọ mi-in to yatọ si BVAS ni INEC fi ko ibo aarẹ jọ fun Tinubu- Atiku
Faith Adebọla Ojumọ kan, ara kan, lọrọ to n jade nibudo igbẹjọ lori awuyewuye to su…
Ibi ayẹyẹ iṣọmọlorukọ lawọn eeyan yii ti n bọ ti wọn fi ji mẹta gbe ninu wọn gbe ni Kwara
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Iroyin to ALAROYE lọwọ bayii fidi rẹ mulẹ pe ibi ikomọ-jade kan ni…
Wahala n bo o! Wọn lawọn kan fẹẹ yọ igbakeji gomina Ondo nipo
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ẹgbẹ kan ti wọn pe ara wọn ni ẹgbẹ Ọmọ Ilajẹ, ti kọwe…
Atiku tun gbọna ẹburu yọ si Tinubu lori ẹjo to pe
Adewale Adeoye Ondije dupo ibo aarẹ to waye lorileede yii lọjọ kẹẹẹdọgbọn, oṣu Keji, ọdun 2023…
Aarẹ Tinubu ṣepade bonkẹlẹ pẹlu awọn gomina ẹgbẹ PDP marun-un to pada leyin Atiku
Adewale Adeoye Olori orileede yii, Aarẹ Bọla Ahmed Tinubu, ti ṣepade bonkẹlẹ kan pẹlu awọn gomina…
A fara mọ bijọba ṣe yọwo iranwọ epo bẹntiroolu- Ẹgbẹ onimọto Eko
Adewale Adeoye Pẹlu bi awọn araalu gbogbo ṣe ti n fẹhonu han lori igbesẹ awọn alaṣẹ ijọba…
Ijọba apapọ kede ọjọ Aje gẹgẹ bii isinmi lẹnu iṣẹ
Adewale Adeoye Awọn alaṣẹ ijọba apapọ orileede yii ti kede ọjọ Aje, Mọnde, ọjọ kejila, oṣu…