Ọladiji Ọlamide di olori ileegbimọ aṣofin ipinlẹ Ondo tuntun

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Aṣofin to n ṣoju awọn eeyan ijọba ibilẹ Ila-Oorun Ondo, Ọnarebu Ọladiji Ọlamide,…

Ẹ wo Damilọla, eeyan to le lọgọrun-un lo ti lu ni jibiti

Monisọla Saka Obinrin ẹni ọdun mẹtalelogun (23) kan, Akinnowọnu Damilọla Victoria, to n ta oriṣiriṣii nnkan…

O ma ṣe o, ibọn ba ẹṣọ so-safe kan nibi ti wọn ti lọọ koju ajinigbe, lo ba gbabẹ ku

Faith Adebọla  Oju bọrọ, ti wọn ni ko ṣee gbọmọ lọwọ ekurọ, ti waye latari bawọn…

Aarẹ Tinubu nikan lo laṣẹ ati kede afikun owo epo bẹntiroolu-Falana

Adewale Adeoye Ilu mọ-ọn-ka lọọya ajafẹtọọ-ọmọniyan nni, Fẹmi Falana, ti sọ pe ki i ṣohun to…

Iyawo mi ti le iya mi nile, o tun maa n rinrin oru, mi o ṣe mọ-Kọlade

Adewale Adeoye Awọn agba bọ wọn ni ọrọ ti oloko fi n sẹkun sun ni aparo…

Ọwọngogo epo: Ẹgbẹ oṣelu Labour lo wa nidii iwọde ti awọn oṣiṣẹ fẹẹ ṣe-Ọnanuga

Monisọla Saka Bayọ Ọnanuga, ti i ṣe adari eto iroyin fun awọn ikọ ipolongo ibo aarẹ…

Afurasi ọlọpaa to pa Bọlanle Raheem ni ki i ṣe inu ibọn oun lọta  naa ti jade

Monisọla Saka L’Ọjọruu, Wẹsidee, ọjọ kọkanlelọgbọn, oṣu Karun-un, ọdun yii, ni Onidaajọ Ibironkẹ Harrison, ti ile-ẹjọ…

Ma a ba Tinubu ṣiṣẹ pọ to ba ranṣẹ si mi – Bọde George

Monisọla Saka Oloye Bọde George, ti i ṣe igbakeji alaga ẹgbẹ oṣelu PDP, ẹka ti apa…

Awọn agbebọn ji aṣaaju awọn obinrin ẹgbẹ oṣelu APC meji lọ

Monisọla Saka Awọn aṣaaju obinrin ninu ẹgbẹ oṣelu APC nipinlẹ Kaduna, Hajiya Lami Awarware, ati Hajiya…

‘Awa gomina APC fara mọ bi Aarẹ Tinubu ṣe yọ owo iranwọ epo bẹntiroolu’

Adewale Adeoye Fun igba akọkọ lati igba ti Aarẹ Bọla Ahmed Tinubu ti kede pe ijọba…

Tinubu yan Femi Gbajabiamila sipo olori awọn oṣiṣẹ

Adewale Adeoye Olori orileede yii, Aarẹ Bọla Ahmed Tinubu, ti yan Olori  ileegbimọ aṣoju-ṣofin ilẹ wa,…