Ọlawale Ajao, Ibadan Lẹyin ti wọn ti wọn ko awọn oṣiṣẹ ileeṣẹ redio Amuludun, n’Ibadan, ni…
Author: admin
Ko si Aarẹ to ṣe daadaa fawọn araalu to Buhari -Ganduje
Adewale Adeoye Gomina ipinlẹ Kano, Alhaji Abdullahi Ganduje, ti sọ pe ko si ani-ani kankan nibẹ rara…
Aarẹ Buhari ko ṣatilẹyin kankan fun ẹgbẹ wa-Miyetti Allah
Aarẹ Buhari ko ṣatilẹyin kankan fun ẹgbẹ-Miyetti Allah Adewale Adeoye Ẹgbẹ awọn Fulani daran-daran, ‘Coalition Of…
Ijọba apapọ kede ọjọ Aje gẹgẹ bii isinmi lẹnu iṣẹ
Adewale Adeoye Bi ohun gbogbo ba lọ bo ṣe yẹ, ọjọ Aje, Mọnde, ọjọ kọkandinlọgbọn, oṣu, Karun-un, ọdun…
Awọn agbẹjoro mi yoo tu aṣiri eru to wa lasiko ibo aarẹ-Atiku
Adewale Adeoye ‘Pe ile–ejọ to ga ju lọ lorileede yii, Supreme Court, da ẹjọ ti mo pe lori Alhaji…
O ma ṣe o, lẹyin ti Samuel f’owo ile-iwe rẹ ati tọrẹ ẹ ta tẹtẹ, lo binu para ẹ
Ismail Adeẹyọ Boya owe afago kẹyin aparo, ohun oju n wa loju n ri lọrọ akẹkọọ…
Ẹ faaye gba awọn ọmọ Naijiria to fẹẹ kawe pẹlu awọn ẹbi wọn – Ẹgbẹ akẹkọọ.
Monisọla Saka Ẹgbẹ awọn akẹkọọ lorilẹ-ede Naijiria, National Association of Nigerian Students (NANS), ti ke si…
Awọn eeyan ilu Iwo ti ko mi si gbese – Oluwoo
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Oluwoo ti ilẹ Iwo, Ọba Adewale Akanbi, ti sọ pe ohun ki i na…
Wọn foju mi ri mabo latimọle ọlopaa-Ṣeun Kuti
Adewale Adeoye Gbajumọ olorin Afrobeat nni, Ṣeun Kuti, tawọn ọlọpaa orileede wa fọwọ ofin mu lori ẹsun pe…
Mi o jẹ Murphy Afọlabi lowo ko too ku, wọn parọ mọ mi ni – Adunni Ade
Monisọla Saka Arẹwa oṣere tiata ilẹ wa, ṣugbọn ti wọn bi nilẹ Amẹrika, Adunni Adewale, tọpọ eeyan…
Aisha Buhari beere fun ajẹmọnu ati owo ifẹyinti fawọn iyawo aarẹ
Monisọla Saka Iyawo Aarẹ orilẹ-ede wa to n palẹmọ ati kogba sile, Aisha Buhari, ti gbẹnu…