Ọmọ ọdun mọkandinlogun gbe majele jẹ nitori owo idokoowo ‘Forex’ to padanu

Stephen Ajagbe, Ilorin Ọmọ ọdun mọkandinlogun kan to jẹ akẹkọọ Fasiti Ilọrin, Gbenga Favour Ọlaoye-Akanbi, la…

‘Ẹ fura o, awọn kan ti fẹẹ maa fi orukọ EFCC lu araalu ni jibiti ni Kwara’

Stephen Ajagbe, Ilorin Ajọ to n gbogun ti iwa jibiti ati ṣiṣe owo ilu baṣubaṣu, ẹka…

Ijọba yoo ti afara ẹlẹẹkẹta fun wakati mejilelaaadọrin, apa kan marosẹ Eko s’Ibadan fun wakati mejidinlaaadọta

Oludari ileeṣẹ to n ri si ọrọ iṣẹ ode nipinlẹ Eko, Olukayọde Popoọla, ti kede pe…

Ijọba bẹrẹ atunṣe ileeṣẹ omi-ẹrọ l’Ọyun/Ọffa, nipinlẹ Kwara

Stephen Ajagbe, Ilọrin Lati fopin si iya to maa n jẹ araalu lasiko ọgbẹlẹ, ijọba ipinlẹ…

Ijọba ṣekilọ: Ẹni to ba kọ lati lo ibomu l’Ekoo le fẹwọn jura o

Faith Adebọla, Eko Ijọba ipinlẹ Eko ti kilọ pe kawọn eeyan ma ṣe ro pe ṣereṣere…

Tiṣa fipa ba ọmọ ọdun mejila lo pọ n’Ilọrin, awọn ọlọpaa ti mu un

Stephen Ajagbe, Ilorin Ọwọ ọlọpaa agbegbe Adewọle, niluu Ilọrin, ti tẹ olukọ ẹni ọdun mejilelọgbọn kan,…

Ijamba mọto gbẹmi eeyan meji loju ọna Gbọngan si Ifẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Eeyan meji lo gbẹmii mi ninu ijamba ọkọ kan to ṣẹlẹ laaarọ ọjọ…

Awọn ile-ẹjọ kaakiri ipinlẹ Eko yoo bẹrẹ isinmi ọdun

Faith Adebọla, Eko Titi ni awọn ilẹkun ile-ẹjọ gbogbo yoo wa nipinlẹ Eko bẹrẹ lati Ọjọbọ,…

Awọn ọmọ ‘yahoo’ mejilelọgbọn balẹ sahaamọ EFCC l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko Afi bii igba tawọn apẹja n fi awọn wọn kore ẹja, bẹẹ lajọ…

FRSC yoo ti ibudokọ to ba lodi sofin Covid-19 pa ni Kwara – Ọwọade

Stephen Ajagbe, Ilorin Ọga agba ajọ to n mojuto igboke-gbodo ọkọ loju popo, FRSC, nipinlẹ Kwara,…

Ina jo ṣọọbu mọkanla gburugburu ninu ọja Ipata, n’Ilọrin

Stephen Ajagbe, Ilorin Ṣọọbu mọkanla toun pẹlu ọja inu ẹ nijamba ina kan to ṣẹ yọ…