Ọrọ ẹni ti yoo jẹ imaamu ilu Iniṣa ni Ajiboṣo n ba wọn pari to fi ṣubu lulẹ, to si ku- Adetoyi

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọtun ilu Iniṣa, Oloye Adetoyi Abimbọla, to jẹ ọkan pataki lara awọn ọrẹ…

Ijiya to tọ si arufin laa maa fi jẹ ẹni ti ko ba lo ibomu l’Ọṣun – Ẹgbẹmọde

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Kọmisanna feto iroyin ati ilanilọyẹ nipinlẹ Ọṣun, Funkẹ Ẹgbẹmọde ti ṣekilọ pe oju…

Oyetọla bura fawọn adajọ kootu ibilẹ ko-tẹ-mi-lọrun meji l’Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Gomina ipinlẹ Ọṣun, Alhaji Gboyega Oyetọla, ti sọ pe ijọba oun ko ni…

Ijọba Eko gbẹsẹ le ọkada bii aadoje, wọn ni wọn ṣẹ sofin irinna

Jide Alabi Nitori pe wọn n rin lawọn ibi ti ijọba ti fofin de pe wọn…

Nitori Korona: Ijọba apapọ fofin de ipejọpọ, ile igbafẹ, ayẹyẹ igbeyawo atawọn mi-in

Pẹlu bi arun asekupani Korona ṣe ti tun pada de bayii, to si n fojoojumọ gbilẹ…

Awọn ọdọ adugbo dana sun ọkunrin kan, wọn lo ji ọmọ araadugbo awọn gbe Amuloko, n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Ni nnkan bii aago mẹfa irọlẹ ọjọ Aiku, Sannde, ọsẹ yii niṣẹlẹ ọhun…

Eeyan mẹrin padanu ẹmi wọn nibi ijamba ọkọ ni Mọniya

Ọlawale Ajao, Ibadan Eeyan mẹrin lo ku loju-ẹsẹ ninu ijamba ọkọ kan to waye ni Mọniya,…

Wahala nbọ o, awọn alaṣẹ Fasiti Ifẹ atawọn eeyan ilu naa fẹẹ gbena woju ara wọn nitori ọrọ ilẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Awọn alaṣẹ ileewe Obafemi Awolowo University, Ile-Ifẹ, ti kilọ fun gbogbo awọn eeyan…

Banki apapọ ilẹ wa ti banki alabọọde mejilelogoji pa, wọn ni kawọn to lowo nibẹ waa gbowo wọn pada

Faith Adebọla, Eko  Ileeṣẹ abanigbofo owo ti wọn ba fipamọ (Nigeria Deposit Insurance Corporation) ti gbawe…

Ara Muyiwa Ademọla ko ya o

Ara gbajumọ oṣere nni, Muyiwa Ademọla ko ya o. Bi a si ti n wi yii,…

Awọn ọmọ ita gbajọba n’Ibadan, wọn fọ ọpọlọpọ ṣọọbu lọsan-an gangan

Ọlawale Ajao, Ibadan Bii ilu ti ko lofin ati adari n’Ibadan ri lọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ…