Ọlawale Ajao, Ibadan “Loootọ ni mo fọ ọkọ mi leti. Oniṣekuṣe ọkunrin ni, ọmọ kan bayii…
Author: Alaroye
Gomina Dapọ Abiọdun gbesẹ lori ofin konilegbele opin ọsẹ l’Ogun
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Oni ọjọ Ẹti, Furaidee, ọjọ kẹrinla, oṣu kẹjọ, ni ijọba fopin si konilegbele…
Tọmọde-tagba lo n ṣedaro Dapọ Williams, ọmọ Yoruba daadaa to ku si London
Ilu oyinbo nibẹ lo n gbe, ni London. Ṣugbọn ki i ṣe pe o n gbebẹ…
O ma ṣe o, o ku oṣu meji pere ki ọmọbinrin yii ṣeyawo ni mọto pa a lori ọkada
Faith Adebọla Ibanujẹ ti dori agba kodo fawọn mọlẹbi ọmọbinrin arẹwa ti ẹ n wo fotọ…
Awọn adigunjale to yinbọn pa oṣiṣẹ ileepo Akurẹ d’ero ile-ẹjọ
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Meji ninu awọn adigunjale to yinbọn pa oṣiṣẹ ileepo kan lọjọ kẹtalelogun oṣu…
Ẹ wo Bọọda Tiṣa, o ti rẹwọn he o, ọmọ ọdun mẹwaa lo fipa ba sun l’Akurẹ
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Tiṣa kan ti wọn porukọ rẹ ni Ọmọtayọ Adanlawọ ti gba idajọ ẹwọn…
Adeṣọla Ọlaniyan gbade, o di ọba ilu Ipokia tuntun
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọjọbọ, Wẹsidee, ọsẹ yii, ni Gomina ipinlẹ Ogun, Ọmọọba Dapọ Abiọdun, fun Onipokia…
Ẹ je ka bẹ Pasitọ Adeboye atawọn olori ẹlẹsin to ku, ki wọn ma ba aṣa Yoruba jẹ o
Ọjọgbọn agbaye kan, Purofẹsọ Toyin Falọla, ti sọ pe gbogbo ẹni yoowu to ba fẹran aṣa…
Adajọ ti gba beeli awakọ to pa Tolulọpẹ Arotile
Lẹyin ti ile-ẹjọ gba beeli ọmọkunrin to wa mọto, ati ẹni to ni mọto to pa…
Baba ọgọrin ọdun to fipa ba ọmọ ọdun marun-un lo pọ l’Agege loun fẹẹ fẹ ẹ ni
Faith Adebọla Tika-tẹgbin lawọn eeyan n wo baba ẹni ọgọrin ọdun kan, Ebenezer Ọlaiya Oyewọle, nigba…
Adedeji, ayederu lọọya, n lọ sẹwọn ọdun mẹta ba a ṣe kọwe rẹ l’Abẹokuta
Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Kootu ko fi ẹjọ ayederu lọọya kan, Adedeji Ebenezer, ẹni ti aṣiri ẹ tu…