Awọn ọlọpaa ti mu awọn ọdọ kan lori iwọde ti wọn fẹẹ ṣe ni Lekki

Wọn ti mu awọn ọdọ kan ti wọn jade fun iwọde wọọrọwọ ni agbegbe Lẹkki, niluu Eko, ni nnkan bii aago mẹjọ aarọ ọjọ Abamẹta, Satide, opin ọsẹ yii. Inu ọkọ ti wọn fi n ko awọn ọdaran ti wọn n pe ni Black Maria ni wọn rọ wọn si . Ọkan ninu awọn adẹrin-in poṣonu ilẹ wa nni, Mr Macaroni, wa ninu awọn ti ọlọpaa ko lọ.

Leave a Reply