IWE IROYIN TO N ṢOJU ỌMỌ YORUBA NIBI GBOGBO
Baálẹ̀ Ṣàṣà, Oloye Akinlade Àjàní ti sọ pe ko si ootọ́ ninu ọrọ ti Seriki Ṣàṣà n gbe kiri pe awọn làwọn da ọja Sasa silẹ. Baba naa ni ọ̀rọ̀ to jinna soootọ ni. O fi kun un pe awọn ṣọja lo ṣatileyin fawon Hausa ti wọn fi jo ile ati ṣọọbu awọn Yoruba.
You must be logged in to post a comment.