Adewale Adeoye Ọwọ awọn ọlọpaa ipinlẹ Eko ti tẹ awọn afurasi ọdaran mẹta kan ti wọn…
Category: Ìròyìn
Nitori ọkada ti wọn gba, awọn ọlọkada kọ lu ẹṣọ oju popo ni Kwara
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Niṣe lọrọ di wahala laarin araalu atawọn oṣiṣẹ ẹṣọ oju popo kan lọjọ…
Nitori iyawo mi ni mo ṣe ji ọkada ti Amọtẹkun ka mọ mi lọwọ – Abdullahi
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Rasheed Abdullahi, ẹni ọdun mejidinlọgbọn, lọwọ ẹṣọ Amọtẹkun ipinlẹ Ọṣun ti tẹ bayii…
O ṣẹlẹ, wọn ti mu Bobrisky ni bọda Sẹmẹ
Jọkẹ Amọri Asiko yii ki i ṣe eyi to dara rara fun ọmọkunrin jayejaye Eko to…
Gomina Sanwo-Olu kede iye ti yoo maa fun owo-oṣu oṣiṣẹ to kere ju
Monisọla Saka Gomina ipinlẹ Eko, Babajide Oluṣọla Sanwo-Olu, ti ni ẹgbẹrun marundinlaaadọrun-un (85,000) Naira, lowo oṣu…
O ma ṣe o, oṣere tiata mi-in tun ku lojiji
Agbọ-sọgba-nu ni iku ọkan pataki ninu awọn oṣere ilẹ wa to maa n saaba kopa baba…
Nitori ọrọ Bobrisky, eyi lohun tile-ẹjọ ṣe fun Very Dark Man
Jọkẹ Amọri Lọjọ Aje, Mọnnde, ọjọ kẹrinla, oṣu yii, ni ile-ẹjọ giga kan nipinlẹ Eko paṣẹ…
Lori ọrọ Ọmọborty ti wọn lo gba ọkọ ọmọ mi, eyi ni b’ọrọ ṣe jẹ-Lọla Idijẹ
Ọrẹoluwa Adedeji Arẹwa oṣere to maa n daṣa oriṣiiriṣii ninu ere nni, Toyin Afọlayan, ti gbogbo…
Ijọba apapọ fẹẹ jọwọ iṣakoso papakọ ofurufu marun-un fawọn alaadani
Adewale Adeoye Gbogbo eto lo ti pari patapata lọdọ awọn alakooso ijọba orileede yii lati jọwọ…
Ọlọpaa n wa Ganiyu to figo gun ibatan rẹ pa l’Ekoo
Adewale Adeoye Titi di asiko ta a n koroyin yii jọ lawọn agbofinro ipinlẹ Eko ṣi…
Ọrọ runrun lẹnu Micheal: Mi o ba ọmọ yẹn sun, mo kan ni ko fọwọ pa ‘’kinni’’ mi ni
Adewale Adeoye Yunkẹyunkẹ ti baale ile kan, Ọgbẹni Afọlabi Michael, ẹni aadọrin ọdun, mọ ọn ṣe…