Igbẹjọ gomina Kwara tẹlẹ, Abdulfatai Ahmed, ti wọn fẹsun ikowojẹ kan bẹrẹ n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Igbẹjọ yoo bẹrẹ lori ẹjọ gomina ipinlẹ Kwara tẹlẹ, Abdulfatai Ahmed, ti ajọ…

Nitori ọwọngogo ounjẹ, eyi lawọn ofin ti Oṣemawe ṣe fawọn ọlọja l’ Ondo

 Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Oṣemawe tilu Ondo, Ọba Victor Kiladejọ, ti ibinu lori bi ọwọngogo ọja ṣe…

Tanka gaasi gbina l’Abẹokuta, eeyan ku, ọpọ fara pa

Faith Adebọla O kere tan, ẹni kan ti pade iku airotẹlẹ, ti ọpọ eeyan si fara…

Wọn ni Wolii Egbin Ọrun ti mọ pe oun maa ku

Adewale Adeoye ‘Loootọ emi pẹlu Oloogbe Morẹnikeji Adeleke, ẹni tawọn eeyan mọ si Egbin Ọrun ko…

Lẹyin ọsẹ kan ti wọn dibo abẹle APC l’Ondo, wọn yinbọn pa adari ipolongo fun Ayedatiwa l’Akoko 

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọkan ninu awọn adari ipolongo ibo fun Gomina ipinlẹ Ondo, Ọnarebu Lucky Orimisan…

Eyi ni bi awọn oludije ẹgbẹ oṣelu PDP ṣe wọle ni gbogbo ijọba ibilẹ mẹtẹẹtalelọgbọn ni ipinlẹ Ọyọ 

Ọlawale Ajao, Ibadan Lọjọ Aiku, Sannde, ọjọ kejidinlọgbọn (28), oṣu Kẹrin, ọdun 2024 yii, lajọ eleto…

Lẹyin ti mo fipa ba ọrẹbinrin mi lo pọ tan ni mo ni ki aburo mi naa ṣe bẹe, ọti ti mo mu lo fa a– Ọlajuwọn

Faith Adebọla ‘Ẹ gbọ, ṣe teeyan ba gba lọọya gidi, ṣe aa le bọ ninu iru…

O ma waa ga o, eeyan mọkandinlogun tun jona gburugburu ninu ijamba ọkọ ni Kogi

Faith Adebọla  Leyii ti ko ti i ju ọsẹ kan lọ tawọn eeyan mẹẹẹdọgbọn kan jona…

Lẹyin ti wọn fun wọn ni beeli, Ọmọọba at’ọrẹ ẹ tun gbe egboogi oloro

Faith Adebọla  Ile-ẹjọ giga apapọ kan to fikalẹ siluu Abuja ti wa egbo dẹkun fun ogbologboo…

Ọwọ fijilante awọn eleyii l’Ekiti, batiri ọkọ ni wọn n yọ

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ajọ fijilante ipinlẹ Ekiti, ti kede pe ọwọ ti tẹ eeyan mẹta ti…

A ko fun Bobrisky ni iyara ọtọ, ọdọ awọn ẹlẹwọn bii tiẹ lo wa-Alaṣẹ ọgba ẹwọn

Adewale Adeoye Lati dẹkun ahesọ kan ti awọn eeyan n gbe kiri nipa ọmọkunrin to ti…