Ileefọpo ilẹ wa ti NNPCL ṣi laipẹ yii ti dawọ iṣẹ duro o, paroparo nibẹ da bayii

Ireti awọn ọmọ Naijiria pe didun lọsan yoo so lori ọrọ epo bẹntiroolu pẹlu bi ileesẹ…

Ẹgbẹ oṣelu NNPP ti ni ki Adeleke maa palẹ eru rẹ mọ nileejọba

Ẹgbẹ oṣelu New Nigeria Peoples Party (NNPP), nipinlẹ Ọṣun, ti sọ pe ki Gomina Ademọla Adeleke…

Eyi lohun ti Gomina Adeleke ṣe fawọn oṣiṣẹ ijọba l’Ọṣun 

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ijọba ipinlẹ Ọṣun ti kede pe ọjọ kin-in-ni, oṣu Kejila yii, lati bẹrẹ…

Eyi lohun ti Gomina Adeleke ṣe fawọn oṣiṣẹ ijọba l’Ọṣun 

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ijọba ipinlẹ Ọṣun ti kede pe ọjọ kin-in-ni, oṣu Kejila yii, lati bẹrẹ…

Abadofin ti Aarẹ Tinubu gbe siwaju awọn aṣofin di wahala nla

Adewale adeoye Fun bii wakati kan tabi ju bẹẹ lọ ni rogbodiyan nla ati idarudapọ fi…

Ọbasanju bu epe jolẹ, ẹni ba ni ki n ku lo maa ṣaaju mi ku

Adewale adeoye ‘Kookooko lara ọta mi le, a ki i ba okunrun ẹyẹ lori itẹ. Emi…

Aṣe NNPC n tan wa ni, tanka epo mẹfa pere ni wọn gbe ti wọn pe ni tuu ọndirẹẹdi

Birọ ba lọ logun ọdun, ọjọ kan ṣoṣo loootọ yoo ba a, lọrọ da fun ileeṣẹ…

Wọn ti ṣọọṣi Ridiimu atawọn ile itaja igbalode kan pa l’Ekoo

Adewale adeoye Ni bayii, ileeṣẹ ijọba ipinlẹ Eko ti wọn n ri sọrọ ayika, ‘‘Lagos State…

Ẹ fura o, NAFDAC ti mu awọn to n ṣe ayederu oogun oyinbo l’Ekoo 

Adewale adeoye Ajọ to n ri sọrọ ounjẹ jijẹ ati ohun mimu pẹlu oogun lorileede yii,…

Wahala bẹ silẹ niluu Oṣogbo lori ọrọ Aṣiwaju Musulumi

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Igbimọ oludamọran fun mọṣalaaṣi apapọ ilu Oṣogbo, eyi ti wọn n pe ni…

Wọn ti mu Bobo Chicago, ọmọ Naijiria to n ṣe gbaju-ẹ niluu oyinbo 

Adewale adeoye Odu ni Oluyọmi Ọmọbọlanle Bombata, ẹni ọdun mẹẹẹdọgbọn, tawọn eeyan mọ si Bobo Chicago,…