Ijọba ja Yahaya Bello sokolonbo, wọn ko gbogbo ẹṣọ to wa leyin rẹ kuro

Faith Adebọla Ileeṣẹ ọlọpaa apapọ orileede yii ti paṣẹ pe ki wọn ko gbogbo awọn agbofinro…

Ijamba ọkọ n’Ilaro ati Ogere, eeyan mẹfa dagbere faye

Faith Adebọla  Eeyan mẹfa, ninu eyi ti ọmọọwọ kan wa, lo ti kile aye pe o…

Awọn eleyii ji kẹkẹ Maruwa tuntun mẹta gbe l’Ekoo, Ondo ni wọn ti mu wọn

Faith Adebọla Ọwọ awọn agbofinro ipinlẹ Eko, labẹ idari Kọmiṣanna ọlọpaa, CP Fayọade, ti tẹ gende…

Emmanuel yii ma laya o, ọlọpaa lo fẹẹ yinbọn mọ n’llọrin ti wọn fi mu un

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Afurasi kan, Emmanuel Oluwafẹmi, ti ṣi iṣẹ ṣe bayii o. Ọlọpaa ti ko…

Ọrọ rirun lẹnu Tim, o ni ọmọde toun fipa ba lo pọ lo nṣẹju si oun

Monisọla Saka Kantankantan lo n jade lẹnu ọkunrin afurasi ẹni ogoji ọdun (40) kan, Anietie Tim,…

Wọn ti mu awọn eleyii ni Kwara, ibọn ni wọn fi maa n ja ọkada araalu gba

 Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọwọ palaba awọn ọdaran mẹrin kan, Jibril Sani, Abdullahi Sani, Mohammed Suleiman ati…

Ibrahim du ọlọkada lọrun, lo ba ji ọkada ẹ gbe sa lọ

Adewale Adeoye Nitori ẹsun pe o ji ọkada araalu kan gbe lẹyin to du onitọhun lọrun laipẹ yii,…

Awọn agbebọn pa ọlọde mẹrin, wọn tun ji ọmọ olori ilu gbe sa lọ

Adewale Adeoye Nnkan ko fara rọ l’Ọjọbọ, Tọsidee, ọjọ kejidinlogun, oṣu Kẹrin, ọdun yii, lasiko tawọn agbebọn kan ya wọnu ilu…

O ma ṣe o, ijamba ọkọ fẹmi eeyan mejila ṣofo

Adewale Adeoye Beeyan ba jẹ ori ahun to ba ri bi awọn oṣiṣẹ ajọ ẹṣọ oju popo, ‘Federal Road Safety Corps’ (FRSC), ẹka tipinlẹ Kano, ṣe n fa…

O ma ṣe o! Ijamba ọkọ gbẹmi akẹkọọ Poli l’Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Dẹrẹba ọkọ kan to ti sa lọ bayii la gbọ pe o ṣokunfa…

Ṣẹyin naa ti gbọ! EFCC n wa Yahaya Bello gidigidi

Monisọla Saka Ajọ to n gbogun ti iwa jẹgudujẹra, ṣiṣe owo ilu mọkumọku ati ẹsun mi-in…