Gaa-Akanbi ni Toheeb ti lọọ jale tọwọ fi tẹ ẹ n’llọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Ẹti, Furaidee, ọṣẹ yii, ni awọn ọdọ tinu n bi ni agbegbe…

Nitori ija agba laarin Imaamu ati aṣaaju ẹṣin, wọn ti mọṣalaaṣi pa n’Ikarẹ Akoko

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Irun Jimọh to yẹ ko waye ninu mọsalaasi gbogbogboo to wa niluu Ikarẹ…

Ọdaju abiyamọ ju ọmọ oojọ sigbo ni Kwara 

   Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ajọ ẹsọ alaabo ṣifu difẹnsi, ẹka ti ipinlẹ Kwara, ti doola ẹmi…

Lẹyin to kuro ni Barcelona, awọn ololufẹ ere bọọlu n reti ibi ti Lionel Messi yoo balẹ si

Faith Adebọla Niṣe lawọn ololufẹ ere bọọlu, paapaa awọn ololufẹ ilumọ-ọn-ka agbabọọlu agbaye nni, Lionel Messi,…

Lẹkki ni Samson atọrẹ ẹ ti lọọ digunjale ti wọn fi mu wọn

Faith Adebọla, Eko Ikawọ awọn ọlọpaa ọtẹlẹmuyẹ ni Panti, lagbegbe Yaba, nipinlẹ Eko, lawọn gende meji…

Hijrah 1443 AH: Gomina Oyetọla kede ọjọ Aje ni ọjọ isinmi lẹnu iṣẹ

Florence Babaṣọla Gomina ipinlẹ Ọṣun, Alhaji Adegboyega Oyetọla, ti kede ọjọ Aje, Mọnde, ọjọ kẹsan-an, oṣu…

Arun to n ṣeku pa ẹran ọsin gbode ni Kwara

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọbọ, Tọsidee, ọṣẹ yii, ni ẹgbẹ awọn Dokita to n tọju ẹranko nilẹ…

Ṣọọṣi Ridiimu pese aaye itọju aisan kindirin si ọsibitu OOUTH, wọn tun ra irinṣẹ si i

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ninu akitiyan wọn lati lọwọ si alaafia araalu, ki wọn si ran ijọba…

Makinde yan Gani Adams ni aṣoju Amọtẹkun, o gbe mọto ti yoo fi ṣiṣẹ naa fun un

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Gomina ipinlẹ Ọyọ, Onimọ-ẹrọ Ṣeyi Makinde, ti yan Iba Gani Adams ti i…

Awọn Oloro marun-un dero atimọle n’Idiroko, awọn Musulumi to n kirun ni wọn kọ lu

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lọjọ Iṣẹgun, ọjọ kẹta, oṣu kẹjọ yii, lawọn kan ti wọn n ṣe…

Laureta gun baba alaaanu ẹ pa, o tun gbe mọto ọkunrin naa sa lọ

Njẹ ẹyin gbọ nipa ọmọbinrin kan ti wọn lo gun baba alaaanu ẹ pa laipẹ yii?…