O ma ṣe o, David Ajiboye, oṣiṣẹ Yinka Ayefẹlẹ ku lojiji

Faith Adebola A-gbọ-sọgba nu ni ọrọ iku David Ajiboye, ọkan ninu awọn ọlọwọ ọtun akọrin Tungba…

Oogun awọro ni mo fi ori ati apa Moses ti a pa ṣe, a si ta ọkàn rẹ ni ẹgbẹrun  marun-un naira- Ifadare

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ifadare Afolabi, oloye Ogboni kan to fi ilu Ikirun, nijọba ibilẹ Ifẹlodun, nipinlẹ…

Awọn adigunjale ni Kọlapọ n f’ọkada ẹ gbe n’Ikire tọwọ fi tẹ ẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọjọ gbogbo ni tole, ọjọ kan ṣoṣo bayii ni ti oni nnkan, eyi…

Ibi ayẹyẹ igbeyawo lawọn kan ti n bọ tawọn agbebọn fi ji marun-un ninu wọn l’Omu-Aran

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Alẹ ọjọ Abamẹta, Satide, opin ọsẹ yii, ni awọn ajinigbe ji awọn arinrin-ajo…

Wọn ni nitori Sunday Igboho l’Ọbasanjọ ṣe sabẹwo si ilẹ Olominira Benin

Faith Adebọla  Iroyin to n ja ranyin lori atẹ ayelujara lasiko yii ni ti igbesẹ pataki…

Lẹyin ọdun meje lakata Boko Haham, ọmọọleewe Chibok kan pada de pẹlu ọmọ meji to ti bi lọhun-un

Bi ẹmi ba wa, ireti o pin, lowe to wọ ọrọ Ruth Pogu, ọkan lara awọn…

Eyi ni bile-ẹjọ ṣe tun fọgbọn de awọn ọmọ ẹyin Sunday Igboho mọlẹ l’Abuja

Faith Adebọla Ki i ṣe iroyin tuntun mọ pe ile-ẹjọ giga apapọ kan niluu Abuja ti…

Ajinigbe koju ọlọpaa n’Ibeṣe, wọn pa ẹni kan, wọn ji eeyan meji gbe, ọlọpaa pa meji ninu awọn naa

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọjọ Abamẹta, Satide, ọjọ keje, oṣu kẹjọ yii, gboro loju ọna Ibeṣe-Itori, nipinlẹ…

  Nitori ọkunrin, Joy da omi gbigbona le Justina lori l’Agbado

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Bi oju apa yoo ṣe jọ oju ara fun iyawo ile kan torukọ…

Awọn ọmọde yii si pa iya aadọta ọdun, wọn tun yọ ẹya ara ẹ lọ lati fi ṣoogun owo

Iya ẹni aadọta ọdun kan, Abilekọ Patience Komor, ti kagbako iku ojiji, Ọgbẹni Simon Onos, ẹni…

O ṣẹlẹ, adajọ poora lakooko to n gbẹjọ lọwọ n’llọrin 

 Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ṣe ni ọrọ naa da bii ere oritage nile-ẹjọ Magistreeti kan to wa…