Ẹ fọkan balẹ, a ti pari gbogbo eto, Sunday Igboho o ni i pẹẹ kuro ninu ahamọ – Lọọya Igboho

Dokita Oluṣẹgun Falọla, ọkan ninu awọn agbẹjọro ajijagbara ọmọ Yoruba nni, Oloye Subday Igboho, ti ni…

Fulani darandaran meji fẹẹ fipa ba ọmọbinrin yii lo pọ, nigba ti ko gba ni wọn ṣa a ladaa ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Ẹti, Furaidee, ọṣẹ yii, lawọn Fulani darandaran meji ti wọn o ti…

Ile-ẹjọ ni ki Lai Muhammed atawọn alatilẹyin rẹ lọọ ti ile ẹgbẹ ti wọn kọ pa ni Kwara

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ile-ẹjọ giga kan niluu Ilọrin, nipinlẹ Kwara, ti paṣe pe ki Minisita fun…

Idibo wọọdu l‘Ọṣun: Awọn ọdọ ẹgbẹ oṣelu APC fẹhonu han, wọn ni Oyetọla ko le yan le awọn lori

 Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ṣe lawọn ọdọ kan ninu ẹgbẹ oṣelu APC, nipinlẹ Ọṣun, fọn soju titi…

 Nitori irin to ji ko, Yisa dero kootu l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Wọn ti foju afurasi ole kan, Yisa Awesu, han ni kootu Majisreeti Ado-Ekiti, fun…

Kafaya fibinu lu ọmọ ẹ pa l’Ogijo, o ni irinkurin ẹ ti pọ ju

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta   Aaya loun fẹẹ tun oju ọmọ oun ṣe ni, afigba to kọwọ bọ…

Ọkan ninu awọn ibeji Ajogbajesu olorin ti ku o

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Owurọ kutu ọjọ Ẹti, Furaidee, ọgbọnjọ, oṣu keje, ọdun 2021, ni iku ṣoro…

Ẹ wo Abiọdun ati Adeleke ti wọn ja Kọpa John lole n’Ikẹja

Faith Adebọla, Eko Ẹni ogoji ọdun ni Ọgbẹni Abiọdun Idowu yii, oun ati ọrẹ ẹ, Adeleke…

Ọmọọba ti ọlọpaa kogberegbe yinbọn lu l’Oṣogbo ti ku o

Florence Babaṣọla Ọmọọba Saheed Ọlabomi, ọmọkunrin ti ọlọpaa kogberegbe kan yinbọn lu lagbegbe Islahudeen, niluu Oṣogbo,…

Wọn na baba to fẹẹ ba iyawo ọmọ ẹ lo pọ lẹgba nita gbangba

Ọkunrin ti wọn n na lẹgba yii ki i ṣe ọmọ kekere, agbalagba ẹni ọdun mẹtalelọgọta…

Ẹ wo Adebayọ ti wọn lo lu ale ẹ pa, to tun ba oku ẹ lo pọ

Bo tilẹ jẹ pe ọkunrin yii, Adebayọ Kingsley, n ṣe awọn alaye kan nipa iku to…