Awọn ololufẹ Samuel Kalu to ko Korona wọle adura fun un

Oluyinka Soyemi Awọn ololufẹ agbabọọlu ilẹ Naijiria to n ṣe bẹbẹ ni Bordeaux, ilẹ France, Samuel…

Awọn aṣofin beere boya o kowo jẹ ni o, n lọga ileeṣẹ NDDC ba daku

  Ọrọ buruku ni, koda o mu ẹrin lọwọ, ṣugbọn awọn ti wọn wa nibẹ ko…

Ṣe ẹyin naa ti ra ALAROYE ọsẹ yii? Ẹ gbọ awọn iroyin to wa nibẹ…

Ṣe ẹyin naa ti ra ALAROYE ọsẹ yii? Ẹ tete beere tiyin lọẉọ fẹndọ ko too…

Korona mu oṣiṣẹ DSTV n’Ibadan, wọn ba ni kawọn onibaara wọn lọọ fira wọn pamọ sile

Ọlawale Ajao, Ibadan Oṣiṣẹ ileeṣẹ Multichoice, iyẹn ileeṣẹ to ni ẹrọ amohunmaworan alatagba ti wọn n…

IBO APC: AKEREDOLU LO WỌLE

Ibo abẹle APC ti wọn di lanaa ni ipinlẹ Ondo, Gomina Rotimi Akeredolu lo ma wọle. …

ISSA FUNTUA, ỌKAN NINU AWỌN IGI-LẸYIN-ỌGBA BUHARI, TI KU O

NInu ile ijọba Aso Rock, a-gbọ-sọgba-nu ni iroyin iku ọhun jẹ. Awọn eeyan ibẹ ko tete…

Wọn ma ni Fayoṣe mulẹ pẹlu awọn ọmọ PDP kan nitori Olujimi (Fidio)

Eyi ni fidio ibura tawọn eeyan n sọ pe gomina Ekiti tẹlẹ, Ayọdele Fayoṣe, fi ṣe…

Ibo abẹle Ondo: Kekemeke loun ko ni igbẹkẹle ninu ẹ, Abraham naa binu kuro

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ  Ọkan ninu awọn to n dije sipo gomina ninu eto idibo to n…

Ọwọ ijọba lo wa ti iwa ifipabanilopọ yoo ba dẹkun lorileede yii – Ẹlẹbuibọn

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Araba awo ti ilẹ Oṣogbo, Oloye Ifayẹni Ẹlẹbuibọn ti sọ pe ti iwa…

Ẹ woju wọn o: Awọn ọmọde Fulani adigunjale lọna Ibadan

Awọn Fulani ọmọde kan ti wọn ko ti i pe ọmo ogun ọdun ti wa lọna…

LONI-IN, AKEREDOLU YOO KOJU AWỌN ALATAKO Ẹ NINU APC L’ONDO

Boya Arakunrin Rotimi Akeredolu yoo tun ṣe gomina ipinlẹ Ondo lẹẹkan si i tabi ala ti…