Nura Walwala lorukọ ọkunrin to duro laarin awọn obinrin mẹrin yii, ẹni ọdun mẹrindinlogoji ni, oun…
Category: Ìròyìn
Ọmọbinrin yii pokunso, nitori ti wọn lo ji pata
Bi ẹ ti n wo ọmọbinrin daadaa yii, ko si laye mọ. Ọgbọnjọ, oṣu kin-in-ni, ọdun 2021…
Ọọni loun ko binu si Sunday Igboho mọ, oun ko si ni i sọrọ lori ohun to ṣe
Ki awueywye to gbode kan le dohun igbagbe patapata lori bi Oloye Sunday Igboho ṣe fẹnu…
Ijọba ti ko awọn ti Fulani ṣa ladaa n’Ibarapa lọ sileewosan UCH, n’Ibadan
Faith Adebọla Ọjọ kẹrin lẹyin ti Gomina ipinlẹ Ọyọ, Ṣeyi Makinde, ṣeleri lati mojuto awọn ti…
Arun Korona tun pa eeyan marun-un l’Ekoo
Faith Adebọla Arun Koronafairọọsi to ti di ẹrujẹjẹ kari aye bayii ti tun da ẹmi eeyan…
Awọn eeyan binu si ọmọ Wasiu Ayinde to n bu Sunday Igboho
Aderohunmu Kazeem Pelu ibinu lawọn eeyan fi n ṣepe le ọmọ Alaaji Wasiu Ayinde, Arabinrin Damilọla…
Buhari fi awọn olori ologun ilẹ wa to yọ nipo ṣe Ambasadọ
Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii, ni Aarẹ ilẹ wa, Muhammadu Buhari kede awọn olori ileeṣẹ ologun to…
Aarẹ Buhari ti fi oṣu mẹta kun asiko ọga ọlọpaa patapata, Muhammed Adamu
Aare Muhammadu Buhari ti fi oṣu mẹta mi-in kun asiko ọga ọlọpaa patapata fun ilẹ wa,…
Ọlọpaa n wa awọn to fibọn gba ogun miliọnu lọwọ awọn oṣiṣẹ ijọba Ekiti
Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ekiti ti bẹrẹ iwadii lori iṣẹlẹ idigunjale kan to waye…
Nitori aabọ owo-osu t’Akeredolu n san fawọn oṣiṣẹ, awọn dokita bẹrẹ iyansẹlodi l’Ondo
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ẹgbẹ awọn dokita to n ṣiṣẹ nileewosan ijọba nipinlẹ Ondo ti bẹrẹ iyansẹlodi…
Ẹgbẹ akẹkọọ ijinlẹ ede Yoruba ṣayẹyẹ ọdun aṣa ni Kwara
Stephen Ajagbe, Ilorin Fọfọ ni gbọngan aṣa ati iṣe-ọna, Kwara State Arts Council, to wa ni…