Tinubu at’ọmọ ẹ ṣabẹwo si Sanwo-Olu, o loun ko sa lọ sibi kankan

Faith Adebọla, Eko Gomina ipinlẹ Eko nigba kan ati aṣaaju ẹgbẹ oṣelu APC, Bọla Ahmed Tinubu,…

Awọn eeyan ya bo ile itaja Shoprite n’Ilọrin, wọn fọ banki atawọn ṣọọbu nibẹ

Stephen Ajagbe, ilọrin Bi a ti ṣe kọ iroyin yii, gbogbo agbegbe ile itaja nla Shoprite…

Awọn eeyan fara pa lasiko tawọn janduku ya bo olu ileeṣẹ aṣọbode n’Ilọrin

Stephen Ajagbe, Ilorin Bii igba ti wọn ba wa loju ogun ni ọrọ ri lana-an, ọjọ…

Awọn janduku ya bo ile Tẹslim Fọlarin n’Ibadan, ọkada, ẹrọ ata, maṣinni iranṣọ, jẹneretọ ni wọn ko nibẹ

Kazeem Aderohunmu O jọ pe pupọ ninu awọn araalu ni ko fẹẹ duro de ijọba tabi…

 Nitori wahala to tun ṣẹlẹ, Oyetola ti kede konilegbele mi-in l’Ọṣun

Idowu Akinrẹmi, Ikire Gomina ipinlẹ Ọsun, Isiaq Gboyega Oyetọla tun ti kede konilegbele miiran lọsan-an ọjọ…

Awọn janduku kọ lu ileeṣẹ Saraki n’Ilọrin

Stephen Ajagbe, Ilorin Alẹ ọjọ Ẹti, Furaide, niroyin gba igboro pe awọn janduku kan kọ lu…

Awọn Fulani ti ji Basit, ọmọ Ẹsin-o-gba-mi-laye, olorin Islaam gbe ni Kwara 

Aderounmu Kazeem Ninu idaamu nla ni gbajumọ olorin ẹsin Islam nni, Mummen Damilọla, wa bayii pẹlu bi awọn…

Awọn alawo n binu si Buhari, wọn tun ṣepe le awọn to fẹmi awọn ọdọ ṣọfo

Kazeem Aderohunmu Nile awo kan ti wọn pe ni Tẹmpili Ọsẹ meji niluu Ibadan lawọn ẹlẹsin…

Awọn janduku ya bo ile awọn oloṣelu l’Ọṣun, wọn n ba nnkan ini wọn jẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Lati ọjọ Ẹti, Furaidee, ti awọn araalu ti n ko ẹru Corvid-19 niluu…

Ọmọ Buhari ni, ‘Ti Naijiria ba ku, ikoriira lo pa a’

Aderounmu Kazeem Ọgbẹni Fẹmi Adeṣina, oluranlọwọ fun Aarẹ Muhammed Buhari, lo sọrọ kan sinu iwe iroyin…

Awọn aṣofin ọmọ Yoruba fariga, wọn lẹnikẹni ko gbọdọ fiwa janduku ba ilẹ Yoruba jẹ

Aderounmu Kazeem Lati fopin si rogbodiyan to n ṣẹlẹ lawọn ibi kan nilẹ Yoruba, lori bi…