Ọlawale Ajao, Ibadan Lẹyin oṣu mẹta ti awọn ikọ ọmọ iṣọta ta a mọ si ‘One Million…
Category: Ìròyìn
Kẹhinde ja purofẹsọ lole, o tun fipa ba agbalagba lo pọ
Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Iwa ọdaju ti ọkunrin kan, Kẹhinde Oke, hu loṣu kejila, ọdun to kọja,…
Awọn ọmọ ẹgbẹ PDP binu si Agboọla, Igbakeji Gomina Ondo
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọpọlọpọ awọn ọmọ ẹgbẹ oṣelu PDP nipinlẹ Ondo ni wọn fẹhonu han tako…
2023: Ilẹ Yoruba ṣetan lati gbajọba, ọrọ ku sọwọ Tinubu, Fayẹmi – ARG
Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ẹgbẹ Afẹnifẹre Renewal Group (ARG) ti sọ pe ilẹ Yoruba ṣetan lati gba…
Magu, olori EFCC tẹlẹ, ti tun n kawọ sẹyin rojọ
Loni-in ọjọ Aje, Mọnde, ọjọ kẹtala oṣu keje, ọdun 2020, Ọgbẹni Ibrahim Magu ti i ṣe…
Eeyan marundinlaaadọrin ko arun Korona lọjọ kan ṣoṣo nipinlẹ Ọyọ
Ọlawale Ajao, Ibadan Lọjọ Abamẹta, Satide to kọja, nikan ṣoṣo, eeyan marundinlaaadọrin (65) lo ko arun Korona…
Awọn oluranlọwọ igbakeji gomina Kwara ti ko arun Korona
Stephen Ajagbe, Ilọrin Lẹyin ọjọ diẹ ti arun Korona pa olori oṣiṣẹ gomina nipinlẹ Kwara, Aminu Adisa…
Lẹyin ọjọ mẹrin to dawati, ileeṣẹ panapana ri oku Abdullateef ninu odo n’Ilọrin
Stephen Ajagbe, Ilọrin Lẹyin ọjọ mẹrin ti wọn ti n wa Abdulwaheed Abdullateef, ẹni ọdun mẹrindinlọgbọn,…
Ọbaladi Afọn tun waja, lọjọ keji ti Olu Imaṣayi papoda
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọbaladi ti Afọn, nijọba ibilẹ Imẹkọ-Afọn, nipinlẹ Ogun, Ọba Busari Adetọna, naa ti…
Lẹyin ọsẹ mẹta ti Ajimọbi ku ni kọmiṣanna rẹ ku sinu ijamba mọto
Ọlawale Ajao, Ibadan Lẹyin ọsẹ mẹta ti gomina ipinlẹ Ọyọ tẹlẹ, Sẹnetọ Abiọla Ajimọbi ku, ọkan…
Ko sẹni to yọ orukọ mi kuro ninu awọn oludije – Akeredolu
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Gomina ipinlẹ Ondo, Rotimi Akeredolu, ti ni ko si ootọ ninu ahesọ to n…