Nitori  ibo Ondo to n bọ, Akeredolu ṣabẹwo si Tinubu

Ibo ti won yoo di ni ipinlẹ Ondo lati yan gomina tuntun ko ju oṣu meji…

Awọn Boko Haram kọ lu gomina, diẹ lo ku ki wọn mu un

Ọlọrun lo yọ Gomina Ipinlẹ Borno o. Gomina Babagana Zulum n pin ounjẹ kaakiri awọn adugbo…

Wọn ni ọdẹ ori lo n yọ ṣọja to yinbọn pa ọga ẹ ni Borno lẹnu

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ṣọja kan ti ileeṣẹ ologun ilẹ wa ko darukọ rẹ ti yinbọn pa…

Maṣinni ti wọn fi n ṣe ọṣẹ lo ge akẹkọọ Fasiti Ibadan yii si wẹwẹ nibi to ti n ṣiṣẹ

Titi di ba a ṣe n sọ yii lawọn eeayn ṣi n tara ikunlẹ abiyamọ lori…

Ẹ woju Pasitọ Adetokunbọ to jiiyan gbe ninu ṣọọṣi ẹ ni Ṣagamu, o ni koun le rowo ẹran Ileya fawọn alaini ni

Kayeefi ni ọrọ naa jẹ o. Ohun to si ṣe jẹ kayeefi ni pe pasitọ ni…

O ma ṣe o, Oloye Ayọ Fasanmi ti ku o

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọkan pataki ninu awọn aṣaaju Yoruba, to tunjẹ ọkan ninu awọn olori ẹgbẹ…

Nitori bi wọn ko ṣe fun un ni tikẹẹti ni PDP, Agboola Ajayi fẹẹ dara pọ mọ ẹgbẹ ZLP

Igbakeji Gomina ipinlẹ Ondo, Agbọọla Ajayi, ti ko ọrọ rẹ to sọ lọsẹ to kọja pe…

O ma ṣe o, wọn ni Ọlabọde luyawo ẹ pa toyuntoyun l’Akurẹ

Awọn ọlọpaa ti mu ọkunrin kan ti wọn n pe ni Oluwaṣeun Ọlabọde o. Ẹsun pe…

‘Ẹ ma waa ki mi nile lọjọ ọdun o!’, Buhari ṣekilọ

Aarẹ Muhammadu Buhari ti ṣekilọ pe ki awọn eeyan ma waa ki oun nile lọjọ ọdun…

Wọn dana sun awọn adigunjale ti wọn fọ banki l’Okeho, ti wọn tun pa ọlọpaa kan

Nnkan ko ṣenuure fun aọn adigunjale kan ti awọn araalu dana sun ni Ọjọruu, Wẹsidee, ọsẹ…

Ijọba yoo ṣi awọn ileejọsin loṣu to n bọ nipinlẹ Ogun– Dapọ Abiọdun

Adefunkẹ Adebiyi, Ogun Ọjọruu, Wẹsidee, ọsẹ yii, ni Gomina ipinlẹ Ogun, Omọọba Dapọ Abiọdun, kede lọfiisi…