Eemọ ree o: wọn ni gomina ilẹ Hausa kan ni olori awọn Boko Haram

Ọkunrin kan to ti fi igba kan jẹ igbakeji ọga pata ni ileefowopamọ apapọ ilẹ wa…

Ẹyin ọmọde, ẹ le awọn arugbo wọnyi kuro nile ijọba, Ọbasanjọ lo sọ bẹẹ

Olori ilẹ wa yii nigba kan, Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ, ti sọ pe bi awọn ọdọ, awọn…

Ijọba Makinde ṣefilọlẹ ọja Akẹsan tuntun niluu Ọyọ

Tilu-tifọn ni Gomina ipinlẹ Ọyọ, Ẹnjinnia Ṣeyi Makinde, fi ṣefilọlẹ Ọja Akẹsan tuntun, niluu Ọyọ, eyi…

Wọn le ọga-agba Yunifasiti Eko lẹnu iṣẹ, ṣugbọn Purofẹsọ ta ku, o loun o lọ

Igbimọ apaṣẹ pata fun ile-ẹkọ giga yunifasiti Eko (University of Lagos) ti le ọga-agba ileewe naa,…

Alaye iya Abdulwasiu, ọkọ obinrin toju ẹ yatọ n’Ilọrin (Fidio)

Iku Buruji Kashamu: Idaamu ti ba awọn oloṣelu o

Ki i ṣe e pe ọkan wọn le naa tẹlẹ, ṣugbọn iku to waa pa ọkunrin…

Konikaluku fidi mọle, ko ni i si ipejọpọ fun ayẹyẹ Ọṣun Oṣogbo- Adebisi

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Latari bi awọn to n lugbadi arun Korona ṣe n pọ si i…

Ọwọ tẹ awọn ọmọ ‘yahoo’ mejilelọgbọn niluu Ogbomọṣọ, akẹkọo fasiti lo pọ ninu wọn

Owe Yoruba kan lo sọ pe ọjọ gbogbo ni tole, ṣugbọn ọjọ kan bayii ni tolohun.…

Korona tun pa Alaga Ijọba Ibilẹ Idagbasoke Onigbongbo

Ọkan ninu awọn alaga ijọba ibilẹ nipinlẹ Eko, Ọgbẹni Francis Babatunde Oke, to jẹ alaga Ijọba…

Wọn fẹsun buruku kan Purofẹsọ ọmọ Yoruba, wọn lo gbowo lọwọ awọn afẹmiṣofo

Wọn ti fi ẹsun buruku kan Purofẹsọ ọmọ Yoruba kan o, Ishaq Akintọla ti yunifasiti LASU,…

Wahala Ire-Ekiti: Awọn ọlọpaa ni ki i ṣe ọta ibọn awọn lo pa awọn to ku

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ekiti ti kede pe ọta ibọn kọ lo pa awọn…