Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Inu ọfọ nla lawọn mọlẹbi ọkunrin ẹni ọdun marundinlaaadọta kan, Olufalayi Ọbadare, wa…
Category: Ìròyìn
Iru ajalu wo waa leleyi! Koronafairọọsi pa aṣofin Eko, Senetọ Bayọ Ọshinọwọ (Pẹpẹrito)
Faith Adebọla, Eko ‘Koro wa o, koro is real, koro lo pa ẹgbọn mi o, ẹni…
Awọn panapana ti ri oku ọkan lara awọn ero ọkọ to ko si odo n’Ilorin
Stephen Ajagbe, Ilọrin Awọn oṣiṣẹ panpana ti ri oku Okechukwu Orwabo, ọkan lara awọn eeyan mẹta…
Lori gbọngan aṣa tawọn aṣofin fẹẹ fi sọri Fayẹmi, APC ati PDP sọko ọrọ sira wọn
Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti O jọ pe ija ko ti i pari rara lori bi ẹgbẹ oṣelu…
Lọjọ ayajọ ijọba tiwa-n-tiwa, ẹlẹwọn mejidinlọgbọn gba idariji nipinlẹ Ondo
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Lati ṣami ayajọ ijọba awa-ara-wa, Gomina Rotimi Akeredolu ti kede idariji fun mejidinlọgbọn…
Kẹhinde fipa ba abirun lo pọ l’Ọta, Musa naa tun fipa ba ọmọ ọdun mẹjọ lo pọ n’Ijẹbu-Ode
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Fun pe o fi tipatipa ba ọmọbinrin kan ti ara rẹ ko da…
Lẹyin ọdun marun-un lọgba ẹwọn, adajọ ni Gideon ko jẹbi ẹsun idigunjale
Florence Babasola, Osogbo Adajọ ile-ẹjọ giga kan niluu Oṣogbo, Onidaajọ Kudirat Akano ti sọ pe ki…
Ẹẹmeji ọtọọtọ lọkọ mi ti lu mi toyun-toyun, mi o fẹ ẹ mọ – Adenikẹ
Ọlawale Ajao, Ibadan “Ọkọ mi ko mọ ju ounjẹ lọ, ọna ti mo gba rowo se…
Awọn onikorona mẹrin sa lọ nibi ti wọn ti n gba itọju n’Igbẹti
Ọlawale Ajao, Ibadan Mẹrin ninu awọn to lugbadi ajakalẹ arun Korona ti sa kuro nibi ti…