Yakubu wa lara awọn ẹlẹwọn Kuje to sa lọ, Sango-Ọta lọwọ ti tẹ ẹ

Gbenga Amos, Abeokuta Gbogbo ere ti Yakubu Abdulmumuni, ẹni ọdun mejidinlọgbọn, sa kuro lọgba ẹwọn Kuje,…

Awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun yinbọn pa Isiaka n’Ilọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’Ọjọ Isẹgun, Tusidee, ọsẹ yii, lawọn ọmọ ẹgbẹ okunkun yinbọn pa akẹkọọ yunifasiti…

Nitori eto aabo, ijọba bẹrẹ iforukọsilẹ fawọn ọlọkada ipinlẹ Ọyọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Nitori ọrọ eto aabo, paapaa bi awọn eeyan ṣe n lo alupupu ta…

Mi o le polongo ibo fun Tinubu mọ, nitori Musulumi to fẹẹ fi ṣe igbakeji-Sẹnetọ Abbo

Monisọla Saka Ishaku Elisha Abbo, Sẹnetọ to n ṣoju apa Ariwa Adamawa ti kọwe fipo silẹ…

Ẹgbẹrun lọna mọkanlelogun agbofinro ni yoo pese aabo nibi idibo gomina Ọṣun – Alkali Baba

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọga agba patapata funleeṣẹ ọlọpaa lorileede yii, Usman Alkali Baba, ti sọ pe…

Emi ni mo ge ọwọ ati ẹsẹ Mesesi, nitori mi o ba owo pupọ lapo rẹ-Dauda

Gbenga Amos, Abẹokuta  Iya agbalagba ẹni ọdun mọkanlelaaadọrin (71) kan, Abilekọ Mesesi Adisa, ti ri iku…

O ma ṣe o! Aṣofin ipinlẹ Ọyọ ku lojiji n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Aṣofin to n ṣoju ẹkun idibo Ila-Oorun Guusu Ibadan Keji, (Ibadan South East…

 Eeyan mẹrin ku sinu ijamba ọkọ l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn ero mẹrin ni wọn ku sinu ijamba ọkọ kan to ṣẹlẹ lagbegbe…

Tinubu kede Shetima gẹgẹ bii igbakeji rẹ

Jọkẹ Amọri  Oludije funpo aarẹ lorukọ ẹgbẹ APC ninu eto idibo ọdun to n bọ, Aṣiwaju…

Tinubu kede Shetima gẹgẹ bii igbakeji rẹ

Jọkẹ Amọri Oludije funpo aarẹ lorukọ ẹgbẹ APC ninu eto idibo ọdun to n bọ, Aṣiwaju…

Ọmọ Naijiria meji lo ti ku si Mẹka

Monisọla Saka Ajọ to n ri si eto irinajo lọ si ilẹ mimọ Mẹka, ni Naijiria…