Emi ni mo maa n ji ọmọ gbe, baba mi lo maa n ta a, ọgbọn ẹgbẹrun lo maa n fun mi -Adeọla

  Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọpọ awọn to wa nibi ti afurasi ajọmọgbe kan, Adeọla Ọmọniyi, ti n…

Ẹṣọ Amọtẹkun Ondo ti sọrọ: Eyi lohun ta a mọ nipa akẹkọọ poli to ku l’Ọwọ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Alakooso ẹṣọ Amọtẹkun nipinlẹ Ondo, Oloye Adetunji Adelẹyẹ, ti ṣalaye bi ọrọ ṣe…

Eid IL Kabir: Oluwo rọ gbogbo ọmọ Naijiria lati gba ifẹ laaye, ki wọn si jẹ olotitọ

Florence Babaṣọla, Ọṣogbo Oluwoo ti ilu Iwo, Ọba Abdulrosheed Adewale Akanbi, ti ke si gbogbo awọn…

Tinubu ti gba lati fi ẹlẹsin Musulumi bii tiẹ ṣegbakeji aarẹ – Ganduje

Faith Adebọla Bi ko ba si ayipada mi-in, aarẹ ati igbakeji aarẹ to jẹ ẹlẹsin kan…

Mọto tẹ ọlọkada pa lọjọ ọdun Ileya l’Oṣogbo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ijamba ọkọ to ṣẹlẹ lagbegbe Agunbẹlewo, niluu Oṣogbo, lọsan-an ọjọ Abamẹta, Satidee, ọjọ…

Agbara ojo doju ọkọ ayọkẹlẹ atero inu ẹ de l’Agege, bẹẹ leeyan mẹrinla ku somi ni Mile 2

Faith Adebọla, Eko Lasiko ti ọpọ eeyan n ṣe yala-yolo ọdun Ileya, ti wọn n ki…

Kẹhinde tọwọ ọmọọmọ rẹ bọ omi gbigbona l’Ondo, o lo ji ẹran jẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Iya agbalagba, Abilekọ Christianah Kẹhinde, lọwọ awọn agbofinro ti tẹ niluu Ondo fun…

Naijiria n ṣaisan, ẹsẹ-kan-aye ẹsẹ-kan-ọrun lo wa -Imaamu Agba Fasiti Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Ko si ẹni ta a le jẹrii pe yoo ṣe daadaa ninu gbogbo…

Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ba ọmọ to parọ pe wọn ji oun gbe nitori ko le gbowo lọwọ awọn obi ẹ

Monisọla Saka Niṣe ni ọmọkunrin ẹni ọdun mọkandinlọgbọn (29) kan, Ṣẹgun Mafimidowo, n ka boroboro l’Ọjọbọ,…

Pasitọ Anifowoṣe ti wọn ba awọn ọmọde ni ajaalẹ ṣọọṣi rẹ ti foju bale-ẹjọ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Olusoaguntan ijọ The Whole Bible Believer, to wa lagbegbe Valentino, niluu Ondo, David…

Awọn agbebọn ji eeyan mẹrin gbe l’Ekiti, ogun miliọnu ni wọn n beere

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ibẹru ati ipaya ti bo ọkan awọn eeyan ipinlẹ Ekiti pẹlu bi awọn…