Idije UEFA Champions League yoo bẹrẹ logunjọ, oṣu yii, awọn alaṣẹ si ti ṣeto ipin mẹjọ fawọn kilọọbu ti yoo kopa nibẹ.
Awọn ipin ọhun niyi:
Ipin A: Bayern Munich, Atletico Madrid, Red Bull Salzburg, Lokomotiv Moscow
Ipin B: Real Madrid, Shakhtar Donetsk, Inter Milan, Borussia Monchengladbach
Ipin C: Porto, Man City, Olympiakos, Marseille
Ipin D: Liverpool, Ajax, Atalanta, Midtjylland
Ipin E: Sevilla, Chelsea, Krasnodar, Rennes
Ipin F: Zenit St Petersburg, Borussia Dortmund, Lazio, Club Bruges
Ipin G: Juventus, Barcelona, Dynamo Kiev, Ferencvaros
Ipin H: Paris St-Germain, Man Utd, RB Leipzig, Istanbul Basaksehir