Champions League: Eyi lawọn kilọọbu ti yoo figagbaga

Idije UEFA Champions League yoo bẹrẹ logunjọ, oṣu yii, awọn alaṣẹ si ti ṣeto ipin mẹjọ fawọn kilọọbu ti yoo kopa nibẹ.

Awọn ipin ọhun niyi:

Ipin A: Bayern Munich, Atletico Madrid, Red Bull Salzburg, Lokomotiv Moscow

Ipin B: Real Madrid, Shakhtar Donetsk, Inter Milan, Borussia Monchengladbach

Ipin C: Porto, Man City, Olympiakos, Marseille

Ipin D: Liverpool, Ajax, Atalanta, Midtjylland

Ipin E: Sevilla, Chelsea, Krasnodar, Rennes

Ipin F: Zenit St Petersburg, Borussia Dortmund, Lazio, Club Bruges

Ipin G: Juventus, Barcelona, Dynamo Kiev, Ferencvaros

Ipin H: Paris St-Germain, Man Utd, RB Leipzig, Istanbul Basaksehir

About admin

Check Also

Umar Sadiq dero ileewosan lẹyin ija ni Russia

Oluyinka Soyemi Abẹṣẹ-ku-bii-ojo ọmọ ilẹ wa, Umar Sadiq, ti n gba itọju nileeowsan bayii lẹyin …

Leave a Reply

//unbeedrillom.com/4/4998019
%d bloggers like this: