FA Cup: Arsenal ati Chelsea yoo koju ara wọn fun aṣekagba

Oluyinka Soyemi

Ẹgbẹ agbabọọlu Arsenal ati Chelsea yoo pade nibi aṣekagba idije FA Cup lọjọ kin-in-ni, oṣu to n bọ.

Lọjọ Abamẹta, Satide, ana, ni Arsenal fiya ayo meji si odo jẹ Manchester City, nigba ti Chelsea fagba han Manchester United lalẹ oni pẹlu ami-ayo mẹta si ẹyọ kan nipele ṣemi-faina.

Ipade awọn mejeeji yoo waye ni Wembley Stadium, to wa niluu London, nibi ti aṣekagba ti n saaba maa n waye lati ọdun 1923.

Igba mẹtala ni Arsenal ti gba ife-ẹyẹ yii, Chelsea si gba a nigba mẹjọ.

About admin

Check Also

Nitori to ni oun yoo fopin si eto aabo ni Borno ati Yobe, PDP Ekiti sọrọ si Fayẹmi

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ẹgbẹ PDPipinlẹ Ekiti ti yẹgẹ ẹnu si gomina ipinlẹ Ekiti, Dokita Kayọde …

Leave a Reply

//zeechumy.com/4/4998019
%d bloggers like this: