Fidio: Sunday lgboho n palẹ ogun mọ

Ọkan ninu awọn ajijagbara ilẹ Yoruba, Sunday Igboho, loun yoo de lbarapa lọjọ Ẹti, Furaidee, ọsẹ yii, gẹ́gẹ́ bi oun ti ṣeleri. Bẹẹ lo fi alalẹ Yoruba ṣepe fun awọn to n ṣatilẹying dáwọn Fulani darandaran.

 

CLICK TO DOWNLOAD

Leave a Reply