Ibo abẹle APC: Ọṣinbajo, Tinubu ati Amaechi ni yoo figa gbaga

Jọkẹ Amọri
Ni bayii, o da bii pe idibo abẹle naa, laarin awọn eeyan Guusu nikan ni yoo ti waye pẹlu bi wọn ṣe tun din awọn oludije naa ku lati marun-un si mẹrin.
Ni bayii, Ọjọgbọn Yẹmi Ọṣinbajo, Aṣiwaju Bọla Tinubu ati Rotimi Amaechi ni yoo jọ koju ara wọn nibi ibo abẹ ti yoo waye ni aago mẹfa irọlẹ ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, oni.
Ko sẹni to ti i le sọ boya adinku yoo tun ba awọn oludije tabi bẹẹ kọ.

Leave a Reply