INEC gbe orukọ awọn ti yoo dije funpo gomina nipinlẹ Ọṣun jade

Florence Babaṣọla, Oṣogbo

Nigbaaradi fun idibo gomina ipinlẹ Ọṣun ti yoo waye lọjọ kẹrindinlogun, oṣu Keje, ọdun yii, ajọ INEC ti gbe orukọ awọn oludije latinu ẹgbẹ oṣelu kọọkan jade.

Awọn oludije pẹlu ẹgbẹ oṣelu wọn niwọnyi:

NRM (National Rescue Mission) Abẹde Adetọna Samuel, SDP (Social Democratic Party) Omigbọdun Oyegoke,  LP (Labor Party) Oyelekan Akingbade, APP (Action People’s Party) Adebayọ Adeolu Elisha.

APM (Allied People’s Movement) Awoyẹmi Oluwatayọ, AAC (African Action Congress) Awojide Peter Ṣẹgun, PDP (People’s Democratic Party) Senetọ Nurudeen Ademọla Adeleke, APC (All Progressives Congress) Alh. Gboyega Oyetọla.

Accord Party- Akande Victor Babalọla, ZLP (Zenith Labour Party) Adeṣuyi John Olufẹmi, ADP (Action Democratic Party) – Kehinde Munirudeen Atanda, YPP (Young Progressive Party) Ademọla Bayọnle Adeṣẹyẹ.

Awọn yooku ni PRP (People’s Redemption Party) Ayọwọle Olubusuyi Adedeji, NNPP (New Nigeria People’s Party) Saliu Rasak Oyelami ati BP (Boot Party) Adeleke Adesọji Masilo Aderẹmi.

 

Leave a Reply