Ọga ọlọpaa patapata ti gbẹsẹ le SARS jake-jado Naijiria, o ni eegun wọn ko gbọdọ ṣẹ mọ

Ọga ọlọpaa patapata nilẹ wa, Muhammed Adamu, ti gbẹsẹ le ẹka ileesẹ ọlọpaa ti wọn gbe kalẹ lati maa gbogun ti idigunjale ti wọn n pe ni SARS kaakiri gbogbo ipinlẹ to wa ni Naijiria. O ni eegun wọn ko gbọdọ ṣẹ mọ. Ninu atẹjade to fi sita llọjọ Aiku, Sannde, ọsẹ yii lo ti kede ọrọ yii.

2 thoughts on “Ọga ọlọpaa patapata ti gbẹsẹ le SARS jake-jado Naijiria, o ni eegun wọn ko gbọdọ ṣẹ mọ

  1. Well . Odara be . Sugbon ejekaro nu jinle nitori awon ajinigbe . Awon ole . Ki ijoba bawase agbekale . Todara lori atunse awon kidnapper ati awon ole pelu awo omo cut tiwongba ode kan ti. Afiki awon ijoba na bawawa nkanse si

Leave a Reply