Ko ti i ju oṣu meji pere lọ gẹgẹ bi a ṣe gbọ ti ọkan ninu awọn ṣọja to padanu ẹmi rẹ ninu ijamba ọkọ ofurufu to waye niluu Kaduna ni ọjọ Ẹti Furaidee, to lọ yii agun Onifade ṣegbeyawo.
Aworan awọn fọto oriṣiiriṣii ti ọkunrin naa pẹlu iyawo rẹ ya lo ti n lọ kaakiri ori ẹrọ ayelujara.