Ọpẹ o, ara Kollington Ayinla ti ya, eyi lọrọ to sọ lọsibitu to wa

Adewale Adeoye

Gbogbo awọn ti wọn ri fidio kan ti Alaaji Kollington Ayinla, ti gbogbo eeyan mọ si Kebe-n-Kwara gbe jade, ni wọn n ba a dupẹ lọwọ Ọlọrun pe baba naa ti wa lalafia, ati pe aisan to ṣe e naa ko mu ẹmi rẹ lọ.

Yin-ni yin-ni knie mi-in ni ọga awọn onifuji ọhun fọrọ naa ṣe pẹlu bo ṣe n dupẹ, to ṣi n fi ẹmi imoore rẹ han si gbogbo awọn ọmọ orile-ede yii nileloko ati lyin odi, paapaa ju l, Gomina ipinle Eko, Ọgbni Babjide SanwoOlu, ga agba ileewosan ẹkọṣẹ iṣegun tijọba Eko, Lagos State University Teaching Hospital( LASUTH), Dokita Adetokunbọ Fabanwo, fun itọju pataki to ri gba, ati bi wọn ṣe sa gbogbo ipa wọn lori r, ti aisan buruku to k lu naa ko ran an sọrun ọsan gangan.

Ninu fidio oniṣẹju di kan to e sita lati fi dup lw gbogbo awọn eeyan jankan-jankan to duro ti i lasiko aisan to da a gbalẹ ọhun Kollington ti gbe ouba nla fun lọrun ba ga ogo lori bṣe ran awlyinju aanu gbogbo si i lasiko to fi aisan laip yii.

O ni, ‘Ọlọrun ba naa ni ma a fi ọpẹ ati iyin fun, nitori pe lrun ba yii ni ga ogo to ga ju l. Lyin naa ni ma a dup lw Gomina ipinl Eko, gbẹni Babajide SanwoOlu, fun bo e dide iranlọwọ si mi. Bakan naa ni mo tun dup lwọ ọga agba ileewosan LASUTH, bi gbogbo we n sare stun-un sosi lori mi. Mi o tun ni i gbagbe ipa pataki tawn araalu Eko ko lori mi lasiko ti mo fi wa lori idubule aisan, lọrun ba lo le san gbogbo yin lsan gidi, lagbara lrun, a ko ni i firu r san an funra wa o.

Tẹ o ba gbagbe, aipẹ yii ni ariwo gba ilu kan pe ara ọga awọn olorin Fuji naa ko ya. Wọn ni aisan naa le debii pe ẹrọ to n ran eeyan lọwọ lati mi ni wọn so mọ ọkunrin naa nimu to fi n mi, tawọn dokita si ti sọ pe bakan meji ni aisan to n ṣe ọkunrin ọmọ bibi ipinlẹ Kwara ọhun. Ṣugbọn pẹlu iranlọwọ Ọlọrun atawọn dokita ileewosan ijọba naa, Alaaji Kollington ti n ta ‘kebe’ pada bayii bii orukọ rẹ. Beeyan ba si ri i lorii bẹẹdi ọsibitu naa to ti ṣe fido ọhun, tọhun ko le mọ pe baba tawọn dokita n sọ pe awọn ko ti i mọ ibi ti ọrọ rẹ maa ja si ni bii ọjọ meloo kan sẹyin niyẹn.

Leave a Reply