Ẹni to ba n bu mi n fi akoko ara ẹ ṣofo lasan ni – Biṣọọbu Oyedepo ṣalaye ọrọ

Awọn eeyan Aarẹ Muhammadu Buahri kan ti bẹrẹ si i bu olori ijọ Winnners, Biṣọọbu David…

Akeem ọlọkada to ta tẹtẹ lawin l’Oṣogbo ti foju bale-ẹjọ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọmọkunrin ọlọkada kan, Akeem Jimoh, lawọn ọlọpaa ti wọ lọ si kootu Majisreeti…

Abiọna lu oyinbo ni jibiti, wọn ti sọ ọ sẹwọn ọdun meji n’Ilọrin

Stephen Ajagbe, Ilorin Ọdaran kan, Abiọna Akinyẹmi Festus, tọwọ EFCC tẹ laipẹ yii fẹsun jibiti ori…

Ijọba ipinlẹ Ọyọ sun ọjọ idanwo aṣewọle sileewe girama siwaju

Nitori bi ọjọ ti wọn fẹẹ ṣe idanwo aṣewọle sileewe girama nipinlẹ Ọyọ ṣe papọ mọ…

Awọn ọmọọta fi ororo gbigbona wẹ Qudus nitori ko fun wọn ni pọfupọọfu ọfẹ

Stephen Ajagbe, Ilọrin Ko si beeyan ṣe jẹ ọdaju to, ti onitọhun ba ri ọdọmọkunrin ẹni…

Atunṣe bẹrẹ nileewosan ilu Ọttẹ lẹyin aṣẹ Gomina Kwara

Stephen Ajagbe, Ilorin Nitori ipo to buru jai tileewosan alaboyun ijọba to wa niluu Ọttẹ wa,…

Awọn aṣọbode yinbọn pa awakọ epo, lawọn ọdọ ba fibinu pa ọga wọn ni Ṣaki

Olu-Theo Omolohun, Oke-Ogun Wahala ati idarudapọ ti ko kere lo ṣẹlẹ lọsan-an Ọjọbọ, Tọsidee to kọja yii, lakooko tawọn oṣiṣẹ ileeṣẹ…

Eyi ni bi awọn Fulani to ji mi gbe ni Lanlatẹ ṣe pa ọkọ afẹsọna mi

Obinrin oniṣowo kan, Modupẹoluwa Oyetọṣọ, wa ninu ọfọ iku ọkọ afẹsọna rẹ lọwọlọwọ bayii, adanu naa…

Oyun ti wọn ni mo ṣẹ fun tẹgbọn-taburo, bọrọ ṣe jẹ niyi o – Pasitọ Ajigbọtoluwa

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ṣe ẹ ranti Pasitọ Ebenezer Ogunmẹfun Ajigbọtoluwa ta a mu iroyin ẹ waa…

Ọpẹ o, wọn ti pari ija obinrin toju ẹ yatọ ni Kwara atọkọ ẹ

Stephen Ajagbe, Ilorin Iroyin ayọ to tẹ wa lọwọ laaarọ oni ni pe ija to wa…

Ridwan ha sọwọ ọlọpaa, ọjọ ọdun Ileya lo figi paayan ni Ṣagamu

Adefunkẹ Adebiyi, Abeọkuta Lọjọ ọdun Ileya to kọja yii ti i ṣe ọjọ kọkanlelọgbọn, oṣu keje,…