Adefunkẹ Adebiyi, Abeọkuta Lọjọ ọdun Ileya to kọja yii ti i ṣe ọjọ kọkanlelọgbọn, oṣu keje,…
Loootọ ni mo ba ọmọ ọdun mẹjọ lo pọ, ṣugbọn mi o fi ṣoogun owo- Ọlanrewaju
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọlanrewaju Adebayọ, ẹni ọdun mejilelọgbọn, ko fi bo pe oun ba ọmọ ọdun…
Ijọba fi kun asiko tawọn ọlọja yoo maa fi taja l’Ekoo
Oluyinka Soyemi Lati din wahala ti araalu n koju lori ọrọ konilegbele ti arun Koronafairọọsi da…
O ṣẹlẹ, awọn eeyan Okelisa fi ayajọ ranṣẹ sawọn to n ji waya ina wọn l’Ondo
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Pẹlu ibinu lawọn eeyan agbegbe Okelisa, niluu Ondo, fi tu jade lọjọ Aje,…
Ọlọkada gbẹmi-in mi nibi rogbodiyan ayẹyẹ ọdun Ọṣun
Florence Babaṣọla Ọkunrin ọlọkada kan gbẹmi mi, nigba ti ekeji fara pa lalẹ ọjọ Abamẹta, Satide…
Awọn oṣiṣẹ eleto ilera l’Ọṣun ṣeleri lati fopin si dida abẹ fawọn ọmọbinrin
Florence Babaṣọla Awọn oṣiṣẹ eleto ilera (Health Workers) kaakiri ipinlẹ Ọṣun ti ṣeleri lati bẹrẹ ipolongo…
Ẹ woju Wolii Festus to fẹẹ fọmọ wolii ẹgbẹ ẹ ṣoogun l’Ondo
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn ọlọpaa ni iwadii ṣi n tẹsiwaju lori ọrọ ọmọbinrin kan ti ọrẹkunrin…
Ẹ woju awọn ọdaran tọwọ tẹ l’Ekoo, oku ọrun lawọn maa n ja lole owo nla
Adefunkẹ Adebiyi Awọn ti ẹ n wo fọto wọn yii, Osita Nwafor, Nwogu Joseph, Anthony Odama,…
Nnkan de! Sunday ti wọn mu pe o n pa awọn eeyan l’Akinyẹle ti sa lọ lagọọ ọlọpaa n’Ibadan
Ọlawale Ajao, Ibadan Iroyin ibanujẹ gbaa lo jẹ fawọn olugbe ijọba ibilẹ Akinyẹle, awọn olugbe Ibadan…
Ṣe asasi waa leleyii ni abi eedi, Pele Onikoko si pokunso sinu ṣọọbu rẹ niluu Gbọngan
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ko sẹni ti ko mọ Pele Onikoko niluu Gbọngan nipinlẹ Ọṣun, yatọ si…
Korona ti tun pa ẹni kan l’Ekiti, bẹẹ lawọn to lugbadi ẹ ti kọja igba
Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ipinlẹ Ekiti ti padanu ẹni kẹta sọwọ arun Koronafairọọsi pẹlu bi awọn to…