Wọn ti fi ẹsun buruku kan Purofẹsọ ọmọ Yoruba kan o, Ishaq Akintọla ti yunifasiti LASU,…
Wahala Ire-Ekiti: Awọn ọlọpaa ni ki i ṣe ọta ibọn awọn lo pa awọn to ku
Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ekiti ti kede pe ọta ibọn kọ lo pa awọn…
Sanwo-Olu ni yoo ṣaaju ipolongo ibo Akeredolu l’Ondo
Bi gbogbo nnkan ba lọ bo ṣe yẹ, Satide, ọjọ kẹẹẹdogun, oṣu yii, ni ẹgbẹ oṣelu…
Ofin ti yoo fiya jẹ obi ti ọmọ ẹ ba n sẹgbẹ okunkun n bọ l’Ekoo
Faith Adebola, Lagos Bi abadofin kan tawọn aṣofin Eko ti bẹrẹ iṣẹ lori rẹ bayii ba…
Akeredolu ṣe ifilọlẹ ikọ Amọtẹkun l’Ondo
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ṣe ni papa iṣere Gani Fawẹhinmi to wa l’Alagbaka, niluu Akurẹ, kun fọfọ…
A gbọdọ ṣewadii bawọn ijọba to lọ ṣe ta dukia araalu ni Kwara-Abdulrazaq
Stephen Ajagbe, Ilorin Ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọsẹ yii ni Gomina Abdulrahman Abdulrazaq tipinlẹ Kwara ṣe ifilọlẹ…
Ọkọ obinrin ti oju rẹ yatọ ti yọju o, o loun ko kọ iyawo oun o
Stephen Ajagbe, Ilorin Abdulwasiu Ọmọ-Dada, ọkọ obinrin toun atawọn ọmọ rẹ ni ẹyin oju to yatọ,…
Ohun ti Mimiko ko le fọdun mẹjọ ṣe, Akeredolu loun ti ṣe e o
“Bo ba ṣe pe ijọba to wa ni ipinlẹ Ondo yii tẹlẹ ṣe daadaa ni, a…
Ariyanjiyan bẹrẹ lori idajọ iku ti wọn fun Sharif-Aminu, ọkunrin ti wọn lo bu Anọbi ni Kano
Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Lati irọlẹ ana, ọjọ Aje, Mọnde, ti kootu Sharia kan niluu Kano ti…
Bọọda onikẹkẹ Maruwa n lọ sẹwọn gbere ree o, nigba toun naa fipa ba ọmọ ọdun mẹrinla sun
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ. Ile-ẹjọ giga to wa lagbegbe Oke Ẹda ni ilu Akurẹ ti dajọ ẹwon gbere fun…
Ọmọge Barakat lo daja silẹ, ni Ayọdele ba ṣeeṣi gun Muhammed pa lAgeege
Awọn ọlọpaa ti mu Ẹniọla Ayọdele ati Kayọde Babaṣọla ni Dọpẹmu, Ageege, nitori pe wọn gun…