Ijọba ipinlẹ Ekiti ti le Olukọ-agba (Principal) ileewe girama, Methodist Girls High School, Ifaki Ekiti kuro…
Makinde le ọkan ninu awọn kọmiṣanna rẹ danu
Lẹyin wakati diẹ ti o ti igbele Korona de, Gomina ipinlẹ Ọyọ, Ẹnjinnia Ṣeyi Makinde, ti…
O ṣẹlẹ! Wọn ni Wolii Festus fẹẹ fọmọ wolii ẹgbẹ ẹ ṣoogun owo l’Ondo
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ. Ọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ yii, ni awọn agbofinro ko Wolii kan, Adebayọ Festus,…
O ma ṣe o: Ọkọ tẹ ọmọ iya meji pa n’Ikẹrẹ-Ekiti
Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Iṣẹlẹ ibanujẹ gbaa lo ṣẹlẹ niluu Ikẹrẹ-Ekiti lopin ọsẹ to kọja nigba ti…
Alainitẹẹlọrun ati alaṣeju ni Agboọla Ajayi -Kennedy
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Igbakeji Gomina Ondo, Agboọla Ajayi, ti tun kuro ninu ẹgbẹ oṣelu PDP, o…
Awọn ọlọpaa yinbọn pa ẹni kan n’Ire-Ekiti nitori ọdun Ogun
Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Walaha nla ti bẹ silẹ niluu Ire-Ekiti, nijọba ibilẹ Ikọle, nipinlẹ Ekiti, kori…
Ọmọ ọjọ kan ti wọn gbe jade ninu sọkawee l’Adiyan ṣi n gbatọju lọsibitu
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Epe nla nla lawọn eeyan n ṣẹ fun ọdaju abiyamọ kan to ju…
Nitori Agboọla to dara pọ mọ wọn, awọn ọmọ ẹgbẹ ZLP n binu kuro ninu ẹgbẹ l’Ondo
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọgọọrọ awọn ọmọ ẹgbẹ oṣelu Zenith Labour Party ni wọn ti binu kuro…
Awọn adigunjale ya wọ otẹẹli n’Ilọrin, eeyan mẹta ni wọn yinbọn fun
Stephen Ajagbe, Ilọrin Lalẹ ọjọ Aiku, Sannde, ọsẹ yii lawọn adigunjale kan ti wọn to bii…
Tinubu ṣedaro iku Kaṣamu, o ni ko daa kẹnikẹni sọrọ odi si oku ọrun
Aṣiwaju ẹgbẹ oṣelu APC, Bọla Ahmed Tinubu, ti ṣedaro iku to pa Oloogbe Buruji Kaṣamu, ọkan…
Ogoje awọn ọmọbinrin Naijiria ti ha si Saudi Arabia, ẹru ni wọn n fi wọn ṣe
Mejidijnlogoje (138) awọn ọmọ obinrin lati agbegbe gbogbo ni Naijiria ni wọn ti ha si Saudi…