Stephen Ajagbe, Ilọrin Lẹyin ọjọ mẹrin ti wọn ti n wa Abdulwaheed Abdullateef, ẹni ọdun mẹrindinlọgbọn,…
Ọbaladi Afọn tun waja, lọjọ keji ti Olu Imaṣayi papoda
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọbaladi ti Afọn, nijọba ibilẹ Imẹkọ-Afọn, nipinlẹ Ogun, Ọba Busari Adetọna, naa ti…
Lẹyin ọsẹ mẹta ti Ajimọbi ku ni kọmiṣanna rẹ ku sinu ijamba mọto
Ọlawale Ajao, Ibadan Lẹyin ọsẹ mẹta ti gomina ipinlẹ Ọyọ tẹlẹ, Sẹnetọ Abiọla Ajimọbi ku, ọkan…
Ko sẹni to yọ orukọ mi kuro ninu awọn oludije – Akeredolu
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Gomina ipinlẹ Ondo, Rotimi Akeredolu, ti ni ko si ootọ ninu ahesọ to n…
Ibanikẹdun n rọ bii ojo nipinlẹ Ogun, ọba mẹta lo waja laarin ọsẹ kan
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Bo tilẹ jẹ pe agbalagba ni wọn, ti ko si eyi to ṣanku…
Lẹyin ọjọ mẹwaa nigbele, akọwe ijọba ipinlẹ Ọṣun bọ lọwọ arun Koronafairọọsi
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Akọwe ijọba ipinlẹ Ọṣun, Ọmọọba Wọle Oyebamiji, ti jajabọ lọwọ arun Koronafairọọsi bayii.…
Wọn ṣi n wa awọn eeyan tawọn ajinigbe ji gbe lọ l’Ekiti
Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Lalẹ ọjọ Ẹti, Furaidee, lawọn ajinigbe kan ti wọn to mẹwaa ya bo…
Ọda owo ati ailera ni ko jẹ ki n ṣayẹyẹ ọgọrin ọdun ti mo dele aye – Lanrewaju Adepọju
Ọlawale Ajao, Ibadan Lọjọ Iṣẹgun,Tusidee, ọsẹ to kọja, lakewi agbaye nni, Alhaji Ọlanrewaju Adepọju, pe ẹni ọgọrin ọdun laye.…
Nitori ajẹsilẹ owo-oṣu, awọn oṣiṣẹ fẹẹ gbena woju Akeredolu l’Ondo
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn aṣaaju ẹgbẹ oṣiṣẹ ipinlẹ Ondo ti fẹhonu wọn han si gomina ipinlẹ…
Olu Imaṣayi, Ọba Gbadebọ Oni, ti waja
Olu Imaṣayi, Ọba Gbadebọ Oluṣọla Oni, ti waja. Akọwe iroyin fun Gomina Dapọ Abiọdun, Ọgbẹni Kunle…
Ibo abẹle APC l’Ondo: Eyi ni orukọ awọn ti yoo kopa
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Mọkanla ninu awọn oludije sipo gomina ninu ẹgbẹ oṣelu APC ipinlẹ Ondo ni…