Wizkid, olorin taka-sufee, kan Aarẹ Buhari labuku

Afaim ki dmkunrin olorin taka-sufee nni, Aydeji Ibrahim Balogun, ni tawn eeyan tun m si Wizkid ma w wahala ijba plu bo e kan Aar Muhammed Buhari labuku.

Laip yii ni arun Koronafairọọsi klu Aar oril-ede America, Donald Trump, ati iyawo , Melania, kaakiri agbaye si ni wn ti n ki i, ti wn n adura fun un wi pe aisan hun ko ni i mna mi.

Eyi naa ni Aar Muhammed Buhari e o, bo si ti gbe e sori r abẹyẹfo rẹ, twitter, to ki Donald Trump, to si tun adura fun un pe ki lrun tete mu un lara da, bẹẹ ni Wizkid naa gba ori ẹrọ abẹyẹfo rẹ, twitter l, nib gan-an lo ti kan Aar oril-ede yii labuku. O kọ ọ sibẹ pe “Baba, r Donald Trump ko kan yin rara, awlpaa atawtlmuy Sars ti wn n pa awd ni Naijiria lojoojum ni k  ba wa mojuto, ko sohun to kan yin ninu r America, oril-ede tiyin ni k  kju m.”

Bo ti e k  niyn o, ohun tawn eeyan si n s ni pe afaim ki ohun to e yii ma di ran si i lrun, nitori ohun ti Buhari e ki i e ohun to buru rara. Wn ni, kaakiri agbaye lawn eeyan ti n ki Aar Amrika, toun naa ba si ki i, eyi ko y ko fa iru abuku bẹẹ.

Bakan naa lawon mi-in s pe ko si wahala ninu ki eeyan s ero kan , ohun ti Wizkid e, ero kan  lo gbe jade. Ati pe t mniyan paapaa faaye gba a daadaa lab ofin.

 

About Alaroye

Journalist, Press man and News Researcher of the federal Republic of Nigeria

Check Also

Lanlọọdu ati getimaanu pa ọmọọdun mẹrin, wọn yọ ẹya ara ẹ lati fi ṣoogun owo

Faith Adebọla Diẹ lo ku kawọn araalu tinu n bi dana sun baba getimaanu kan …

7 comments

 1. Akintunde lasisi

  Buhari o ti kan abuku o si ma pada te ti yo fi ate tedi ni Nigeria yi. O ti su awa ara ilu patapata bayi.

 2. Imoran lofun olori riwa kiwalofefa waala fun nibe

 3. Erote mi Nile koye lasi waju gidi rara eni ti won fi se pe ni koye leni adura

 4. Kosi ohun to buru ninu nkan to so yen ,ki ijoba naijiria bawa wa nkan se si ipaniyan L’ori lede yi ni ooooo
  There is nothing bad about his comment,let the Nigerian government take a quick intervention to curb d unlawful killings that rampered every where today.
  GOD BLESS NIGERIA
  GOD BLESS US WE THE VOICELESS NIGERIANS
  ONE NIGERIA WE MOVE FORWARD

 5. Ko si ohun to buru ninu ohun ti Wizkid so, amoran lo gba ijoba buari kise abuku rara, eyin oniroyin yi ema fa wahala si omo olomo lorun

 6. Kosi aburu ninu nkan ti odomode yii so rara sugbon ododo oro ni aare buhari kokin fe gboo.

 7. Oun ti wizid so naa koitipoju tabani kawo dada imonran logba ARE orile edewa pe eje karan aso Nigeria wa na kato bawon ranti orile ede America

Leave a Reply

//zikroarg.com/4/4998019
%d bloggers like this: