Wọn ti fibinu dana sun aafin Ọba Akiolu, ile iya Sanwo-Olu l’Ekoo

Olajide Kazeem

Pẹlu bi wahala ṣe n lọ kaakiri ipinlẹ Eko, awọn ọdọ to n binu yii tun ti kọlu aafin Olowo-Eko, Ọba Rilwan Akiolu.

Owurọ kutu yii niṣẹlẹ ọhun waye n’Isalẹ Eko, nibi ti aafin kabiyesi yii wa.

Yatọ si aafin yii, ile iya gomina Eko ni Suurulere paapaa ti lọ si i.

Leave a Reply