Wọn tun ti kọ lu Ojodu Berger, ọfiisi BRT, VIO ati FRSC

Kazeem Aderohunmu

Bi wọn ti ṣe n jo garaaji BRT ni Ojodu Berger, bẹẹ naa ni wọn ti kọ lu ọfiisi ileeṣẹ ti wọn ti n gba iwe irinna, VIO atawọn ẹṣọ ojupopo, FRSC.

Niṣe ni wahala to n ṣẹlẹ lọwọlọwọ kaakiri ipinlẹ Eko tubọ n fẹju si i.

One thought on “Wọn tun ti kọ lu Ojodu Berger, ọfiisi BRT, VIO ati FRSC

Leave a Reply