Akeredolu si ileeṣẹ Ṣokoleeti si Idanre, l’Ondo

Iyiade Oluṣẹyẹ, Akurẹ

Ilu Alade Idanre, nipinlẹ Ondo, ni GominaRotimi Akeredolu ti ṣe ifilọlẹ ileeṣẹ ti wọn ti n ṣe nnkan ipanu, ṣokoleeti (chocolate), eyi ti wọn pe ni  Sunshine Chocolate Factory.

Igbesẹ yii waye pelu ajọsepọ ipinle Ondo ati ileeṣẹ kan to wa ni orileede Amerika ti wọn pe ni SPAGNVOLA CHOCOLARTIES, eyi ti Akeredolu ni awọn da silẹ lati pese iṣẹ fun awọn ọdọ nipinlẹ ọhun.

Leave a Reply