Loootọ ni mo ba ọmọ ọdun mẹjọ lo pọ, ṣugbọn mi o fi ṣoogun owo- Ọlanrewaju

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọlanrewaju Adebayọ, ẹni ọdun mejilelọgbọn, ko fi bo pe oun ba ọmọ ọdun…

Ijọba fi kun asiko tawọn ọlọja yoo maa fi taja l’Ekoo

Oluyinka Soyemi Lati din wahala ti araalu n koju lori ọrọ konilegbele ti arun Koronafairọọsi da…

O ṣẹlẹ, awọn eeyan Okelisa fi ayajọ ranṣẹ sawọn to n ji waya ina wọn l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Pẹlu ibinu lawọn eeyan agbegbe Okelisa, niluu Ondo, fi tu jade lọjọ Aje,…

Ọlọkada gbẹmi-in mi nibi rogbodiyan ayẹyẹ ọdun Ọṣun

Florence Babaṣọla Ọkunrin ọlọkada kan gbẹmi mi, nigba ti ekeji fara pa lalẹ ọjọ Abamẹta, Satide…

Awọn oṣiṣẹ eleto ilera l’Ọṣun ṣeleri lati fopin si dida abẹ fawọn ọmọbinrin

Florence Babaṣọla Awọn oṣiṣẹ eleto ilera (Health Workers) kaakiri ipinlẹ Ọṣun ti ṣeleri lati bẹrẹ ipolongo…

Ẹ woju Wolii Festus to fẹẹ fọmọ wolii ẹgbẹ ẹ ṣoogun l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn ọlọpaa ni iwadii ṣi n tẹsiwaju lori ọrọ ọmọbinrin kan ti ọrẹkunrin…

Korona ti tun pa ẹni kan l’Ekiti, bẹẹ lawọn to lugbadi ẹ ti kọja igba

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ipinlẹ Ekiti ti padanu ẹni kẹta sọwọ arun Koronafairọọsi pẹlu bi awọn to…

Emi kọ ni mo pa iyawo atawọn ọmọ mi o – Oyediran (Fidio)

Ipari oṣu to kọja ni iroyin naa gbalẹ pe nọọsi kan, Solomon Tunde Oyediran, gun iyawo,…

Bayern lu Barca laluwo pẹlu ami-ayo mẹjọ si meji

Iya ami-ayo mẹjọ si meji ki i ṣe nnkan ti ẹgbẹ agbabọọlu Barcelona ilẹ Spain ro…

Willian balẹ si Arsenal lẹyin ọdun meje ni Chelsea

Oluyinka Soyemi Agbabọọlu Chelsea tẹlẹ, Willian Borges da Silva, ti balẹ si Arsenal lẹyin to tọwọ…

Ẹyin agbaagba Afẹnifẹre, eti yin meloo?

Mo fẹẹ ya bara diẹ kuro lori eto ti a n ba bọ, ki n lo…