Adewale Adeoye ‘‘Fun odidi ọdun mẹjọ gbako ti olori orileede yii tẹlẹ, Ajagun-fẹyinti, Muhammadu Buhari, fi…
Author: admin
Aarẹ Tinubu gbọdọ da owo epo bẹntiroolu pada si bo ti ṣe wa tẹlẹ-TUC
Adewale Adeoye Aarẹ ẹgbẹ awọn oṣiṣẹ kan ti wọn n pe ni ‘ Trade Union Congress’…
Owo iranwọ epo: Eyi nidi ta a ṣe fẹẹ dasẹ silẹ-Ẹgbẹ oṣiṣẹ
Monisọla Saka Ẹgbẹ awọn oṣiṣẹ lorilẹ-ede Naijiria, Nigerian Labour Congress, (NLC), ti fi atẹjade sita lori…
Diẹ lo ku ki wọn fi lilu ran Isiaka sọrun, ewure lo ji gbe n’Ilọrin
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ẹṣinburuku ni wọn fi ogbologboo ole kan, Isiaka, to ji ewurẹ gbe niluu…
Eyi lohun to ṣẹlẹ si ọmọ Alabi Pasuma l’Amẹrika
Faith Adebọla Ọmọ to ba mowo dele lobi rẹ yoo yin, gbogbo obi si ni wọn…
A ni lati ṣatunṣe si owo oṣiṣẹ to kere ju lọ-Tinubu
Monisọla Saka Aarẹ Bọla Tinubu, ti ṣeleri lati ṣagbeyẹwo owo oṣiṣẹ to kere ju, nitori lara…
Nitori owo iranwọ epo bẹntiroolu, ẹgbẹ oṣiṣẹ yoo bẹrẹ iyanṣẹlodi lọsẹ to n bọ
Adewale Adeoye Bọrọ tawọn olori ẹgbẹ oṣiṣẹ lorileede wa n sọ ba jẹ ootọ, Ọjọruu, Wesidee,…
EFCC ti mu ọkan lara awọn minisita Buhari o
Adewale Adeoye Ajọ to n gbogun ti iwa ibajẹ ati ṣiṣe owo ilu mọku-mọku nilẹ wa…
Ọmọkunrin yii buru o, o fun ọmọọdun mẹwaa loogun oorun, o si fipa ba lo pọ
Adewale Adeoye Awọn alaṣẹ ileeṣẹ ọlọpaa agbegbe Nasaru, nijọba, ibilẹ Ningi, nipinlẹ Bauchi, ti sọ pe…
Wike, Makinde ati Ibori ṣepade bonkẹlẹ pẹlu Aarẹ Tinubu l’Abuja
Adewale Adeoye Titi di akoko ta a n koroyin yii jọ, ko ti i sẹni to…
Auxillary pe awọn ọlọpaa nija, o ni wọn ko le mu oun laelae
Ọlawale Ajao, Ibadan Lẹyin ti ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọyọ ti kede Alhaji Mukaila Lamidi, olori ẹgbẹ…