Nibi ti wọn ti n ja nitori ọmọge, Marvelous fi siṣọọsi gun aladuugbo rẹ pa l’Ọka Akoko

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ile-ẹjọ Majisireeti to wa l’Oke-Ẹda, niluu Akurẹ, ti ni ki ọmọkunrin ẹni ọdun…

Nitori ti wọn ko fẹ ko lọ sile, awọn ọlọpaa tun sare gbe Ṣeun Kuti pada lọ si kootu

Monisọla Saka L’Ọjọbọ Tọsidee, ọjọ kejidinlogun, oṣu Karun-un, ọdun yii, lawọn ọlọpaa tun gbe Ṣeun Kuti,…

Iba dara to ba jẹ pe bii ogun ọdun sẹyin ni Tinubu dupo aarẹ- Peter Obi

Monisọla Saka Peter Obi, ti i ṣe oludije dupo aarẹ lẹgbẹ oṣelu Labour Party, sọ pe…

Nitori ti wọn tapa sofin imọtoto ayika, eeyan mẹfa rẹwọn he ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọbọ, Tọsidee, ọjọ kejidinlogun, oṣu Karun-un, ọdun yii, ni kootu alagbeeka kan niluu…

A ti na to igba biliọnu Naira fun ipalẹmọ eto ikaniyan ti ko waye mọ yii-NPC

Adewale Adeoye Ajọ eleto ikanniyan lorileede wa, ‘National Population Commision’ (NPA), ti sọ ọ di mimọ…

Nitori ẹgbẹrun lọna ọgọrun-un Naira, Inuwa sọ ọrẹ rẹ loko pa

Adewale Adeoye Titi di akoko ta a n ko iroyin yii jọ, ṣe lọrọ Ọgbẹni Yunan…

Ile-ejọ kankan ko le da eto ibura sipo Tinubu duro-Ijọba apapọ

Adewale Adeoye Ni bayii, awọn alaṣẹ ijọba apapọ orileede yii ti sọ ọ di mimọ pe…

Ofin ko faaye gba ẹnikẹni lati lu ọlọpaa nita gbangba pẹlu aṣọ ijọba lorun-Adejọbi

Adewale Adeoye ‘Ki i ṣohun to ba ofin ilẹ wa mu rara pe kawọn araalu maa…

Nitori ẹbọ ti wọn ba lorita ilu wọn, idaamu nla ba awọn eeyan Ọwẹna, wọn ni ami buruku ni

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Inu ibẹrubojo lawọn eeyan ilu Ayetoro-Ọwẹna, ti i ṣe ibujokoo ijọba ibilẹ Idanre,…

EFCC tun mu awọn ọmọ Yahoo mẹrindinlọgbọn

Adewale Adeoye Ajọ kan to n gbogun ti iwa ibajẹ ati ṣiṣe owo ilu ni mọku-mọku…

Ti gomina yii ba ti gbejọba silẹ la maa fọwọ ofin mu un lori owo to ko jẹ-EFCC

Adewale Adeoye Ajọ to n gbogun ti iwa ibajẹ ati ṣiṣe owo ilu mọku-mọku lorileede yii,…